Moji Afolayan tí wọ́n bí ní Ọjọ́ karùn-ún oṣù kejì ọdún 1969 (February 5, 1969) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí Yorùbá láti ìlú Ìbàdàn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Mojí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ bíbí olóògbé òní-sinimá àgbéléwò Adeyemi Afolayan[2] tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ade Love nígbà ayé rẹ̀. Moji Afolayan fẹ́ gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò, Razaq Olayiwola tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ojopagogo. [3]

Quick Facts Ọjọ́ìbí, Orílẹ̀-èdè ...
Moji Afolayan
Ọjọ́ìbí(1969-02-05)5 Oṣù Kejì 1969
Ibadan, Oyo, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́
  • osere
  • filmmaker
  • producer
  • director
  • dramatist
Olólùfẹ́Rasaq Olayiwola
Parent(s)Ade Love (father)
Àwọn olùbátanKunle Afolayan (brother)
Gabriel Afolayan (brother)
Aremu Afolayan (brother)
Close

Iṣẹ́ Fíìmù Rẹ̀

Ní ọdún 2016, Afolayan tó ti ṣeré nínú ọ̀pọ̀ àwọn eré Nàìjíríà tí ó fi hàn pẹ̀lú Ojopagogo àti Dele Odule nínú eré fíìmù Yorùbá "Àrìnjó".

Ayé Rẹ̀

Ó ṣe ìyàwó sí Rasaq Olasunkanmi Olayiwola, òṣèré ọkùnrin ti ilẹ̀ Nàìjíríà tí gbogbo ayé mọ̀ sí orúkọ orí ìtàgé rẹ̀, "Ojopagogo".

Àwọn Ìtọ́kasí

Wikiwand in your browser!

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.

Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.