Gabriel Afolayan

Òṣéré orí ìtàgé From Wikipedia, the free encyclopedia

Gabriel Afolayan

Gabriel Afolayan (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kìíní oṣù kẹta ọdún 1980) tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí G-Fresh lágbo orin jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò àti akọrin ìgbàlódé. [1]. Tẹ̀gbọ́n-tàbúrò ni Gabriel àti Kunle Afolayan. Àgbà eléré tíátà nì Adeyemi Afolayan, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ade Love nígbà ayé rẹ̀ ní bàbá wọn.

Quick Facts Orílẹ̀-èdè, Ọmọ orílẹ̀-èdè ...
Gabriel Afolayan
Thumb
Afolayan at the audition for Ojuju in 2013
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Actor, singer [2]
Ìgbà iṣẹ́1997 - present [3]
Parent(s)Adeyemi Afolayan (father)
Àwọn olùbátanMoji Afolayan (sister)
Kunle Afolayan (brother)
Aremu Afolayan (brother)
Close

Àtòjọ àwọn sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa

  • Gold Statue
  • Ojuju
  • Madam Dearest
  • Ija Okan
  • Hoodrush
  • Heroes and Zeros
  • 7 Inch Curve
  • Okafor's Law
  • Closet (TV Series)
  • Tatu
  • Tomi has a gun
  • Nnenna

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.