Aremu Afolayan
From Wikipedia, the free encyclopedia
Aremu Afolayan jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó tún jẹ́ ẹ̀gbọ́n fún òsèrékùrin Kunle Afolayan, tí ó jẹ́ òṣèré àti adarí eré tí ó gba amì-ẹ̀yẹ adarí eré tó peregedé jùlọ.[1][2][3]
Aremu Afolayan | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Aremu Afolayan 2 Oṣù Kẹjọ 1980 Ebute Metta, Ìpínlẹ̀ Èkó, |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Òsèrékùrin, Producer |
Olólùfẹ́ | Kafilat Quadri |
Parent(s) | Adeyemi Afolayan (Ade Love - father) |
Àwọn olùbátan | Moji Afolayan (sister) Gabriel Afolayan (brother) Kunle Afolayan (brother) |
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀
Àrẹ̀mú Afọláyan jẹ́ ọmọ bíbí gbajú-gbajà adarí eré àti olùgbéré-jáde Adé Love tí ó jẹ́ ọmọ ìlú Ìgbómìnà ní Ìpínlẹ̀ Kwara.[4] Kúnlé di.ìlú-mòọ́ká látàrí eré rẹ̀ kam tí ó gbé jáde tí ó pè ní Ìdàmú Akoto ní ọdún 2009.
Ìgbé ayé rẹ̀
Àrẹ̀mú fẹ́ aya rẹ̀ arábìnrin Kafilat Ọláyínká Quadri, tí wọ́n sì bímọ obìnrin kan Iyùnadé Afọláyan.
Àmì ẹyẹ
Ọdún | Àmì ẹyẹ | Ẹka | Èsì | itokasi |
---|---|---|---|---|
2021 | Net Honours | Most Searched Actor | Wọ́n pèé | [5] |
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.