Remove ads
Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìpínlẹ̀ Kébí tí ìfohùnpè rẹ̀ lèdè Hausa àti àwọn èxè míràn ń jẹ́ (Àdàkọ:Lang-ha; Fulfulde: Leydi Kebbi 𞤤𞤫𞤴𞤣𞤭 𞤳𞤫𞤦𞥆𞤭) jẹ́ ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ tí ó wà ní apá òkè ọya àti ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì tí wọ́n wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ pààlà pẹ̀lú àwọn ìpínlẹ̀ míràn bíi: Ìpínlẹ̀ Sokoto, Ìpínlẹ̀ Zamfara Ìpínlẹ̀ Niger àti orílẹ̀-èdè olómìnira Benin.[4] Wọ́n ṣẹ̀dá Ìpínlẹ̀ yí látara Ìpínlẹ̀ Sokoto ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n.oṣù kẹjọ ọdún 1991, tí wọ́n sì sọ olú-ìlú ìpínlẹ̀ náà ní Birnin Kebbi.[5] Of the 36 states of Nigeria, Kebbi is the tenth largest in area and 22nd most populous, with an estimated population of about 4.4 million as of 2016.[6] Orúkọ ìnagijẹ ìpínlẹ̀ náà á ma jẹ́ ilẹ̀ ẹ̀tọ́ (land of equity]][4] Bí a bá ní kí á wo ilẹ̀ ìpínlẹ̀ náà, ìpínlẹ̀ yí jẹ́ ilẹ̀ igbó tí òjò sì ma ń rọ̀ níbẹ̀ dára dára. Lára àwọn ohun tó mú ìpínlẹ̀ yí yàtọ̀ sí àwọn ìpínlẹ̀ tó yiká ni wípé oní iṣàn omi odò tí ó ń bọ̀ láti Ìpínlẹ̀ Sokoto tí omi náà sì ṣàn lọ sí inú adágún odò Kainji. Lára àwọn àrà tí ó tún wà ní ìpínlẹ̀ yí náà ni àwọn ẹja àràmàndà tí àwọn apẹja ma ń pa lásìkò ọdún ẹja Argungu, bákan náà ni àwọn ẹranko bí erinmilókun, erin igbó ati àwọn ẹranko bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ pe sí jùlọ.[7]
Kebbi | ||
---|---|---|
Image showing the yearly Argungu Fishing Festival held in Argungu | ||
| ||
Nickname(s): | ||
Location of Kebbi State in Nigeria | ||
Coordinates: 11°30′N 4°00′E | ||
Country | Nigeria | |
Date created | 27 August 1991 | |
Capital | Birnin Kebbi | |
Government | ||
• Body | Government of Kebbi State | |
• Governor (List) | Nasir Idris (APC) | |
• Deputy Governor | Abubakar Umar Argungu (APC) | |
• Legislature | Kebbi State House of Assembly | |
• Senators | C: Adamu Aliero (PDP) N: Yahaya Abdullahi (PDP) S: Bala Ibn Na'Allah (APC) | |
• Representatives | List | |
Area | ||
• Total | 36,800 km2 (14,200 sq mi) | |
Area rank | 10th of 36 | |
Population (2006 census) | ||
• Total | 3,256,541[1] | |
• Rank | 22nd of 36 | |
Demonym(s) | Kebbian | |
GDP (PPP) | ||
• Year | 2023 | |
• Total | $16.6 billion[2] | |
• Per capita | $2,896[2] | |
Time zone | UTC+01 (WAT) | |
postal code | 860001 | |
ISO 3166 code | NG-KE | |
HDI (2018) | 0.339[3] low · 37th of 37 | |
Website | kebbistate.gov.ng |
Oríṣiríṣi ẹ̀yà bíi: Nupe, Fúlàní, Zaram àti àwọn ẹ̀yà Hausa ni wọ́n ń gbé ìpínlẹ̀ yí. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé àwọn ẹ̀yà bíi: Achipa (Achipawa), Boko-Bala, Dendi, Dukawa, Kambari, Kamuku, Lela, Puku, àti àwọn Shanga náà ń gbé ní agbègbè apá ìwọ̀ àti ìlànà Oòrùn ìpínlẹ̀ náà. Púpọ̀ àwọn olùgbé ìpínlẹ̀ tí wọ́n jẹ́ ìdá ọgọ́rin lé mẹ́rin ni wọ́n jẹ́ ẹlẹ́sìn Mùsùlùmí nígbà tí àwọn tókù jẹ́ ẹlẹ́sìn Krìstẹ́nì ati àwọn ẹlẹ́sìn Bori.[8] Ibi tí ó di Ìpínlẹ̀ Kebbi lóní láyé àtijọ́ ni ó wà lábẹ́ ìṣàkóso ilẹ̀ Ọba Kebbi tí wọ́n jẹ́ Hausa bakwai state, tí tí si ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 1800 kí àwọn ajìjà ẹ̀sin Fúlàní gba dí ẹ̀ lára ilẹ̀ náà sí abẹ́ ìṣàkóso ìjọba Gwandu Emirate lábẹ́ ìṣàkóso Sokoto Caliphate. Lẹ́yìn ìjà ẹ̀sìn yí, àwọn ọmọ ìlú Kebbi ti ń bá àwọn ènìyàn Sókótó jà ní gbogbo ìgbà ṣáájú kí àwọn gẹ̀ẹ́sì àmúnisìn tó fipá gba ilẹ̀ náà tí wọ́n sì ń ṣakóso rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ 1900 títí di 1910 títí di ọdún 1960 tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gba òmínira. [9].
Àdàkọ:Unsourced section
Ìpínlẹ̀ Kebbi ní ìjọba ìbílẹ̀ mọ́kànlélógún àti ilẹ̀ Ọba mẹ́rin (Gwandu, Argungu, Yauri and Zuru),
Àwọn èdè tàbí ẹ̀ka èdè tí wọ́n ń sọ ní ìpínlẹ̀ kébi pọ̀, àmọ́ èdè Hausa ni ó gbajú-gbajà jùlọ. [10]
LGA | Languages |
---|---|
Argungu | Dendi; Zarma |
Bagudo | Bisã; Boko; Dendi; Kyenga |
Birnin Kebbi | Zarma |
Bunza | Zarma |
Donko-Wasagu | C'Lela |
Dukku | us-Saare |
Jega | Gibanawa |
Ngaski | Cishingini; Lopa; Tsikimba; Tsishingini; Tsucuba; Tsuvadi |
Sakaba | Cicipu; C'Lela; Damakawa; ut-Ma'in |
Shanga | Shanga |
Wasagu-Danko | us-Saare; Gwamhi-Wuri |
Yauri | Reshe; us-Saare |
Zuru | C'Lela; ut-Ma'in |
Àwọn èdè míràn tí wọ́n tún ń sọ níbẹ̀ ni èdè Fulfulde, Ut-Hun, àti Sorko.[10]
Ìpínlẹ̀ Kebbi gẹ́gẹ́ bí àwọn ìpínlẹ̀ tókù ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni wọ́n ń lo gómìnà, ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin. [11]
Ìpínlẹ̀ Kebbi ní àwọn ohun àlùmọ́nì oríṣiríṣi tí ó lè mú ìdàgbà-sókè bá ìlú àti àwọn ènìyàn ibẹ̀. Lára rẹ̀ ni: [12]
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.