From Wikipedia, the free encyclopedia
This Day jẹ́ òkan lára àwon ìwé-ìròyìn olójoojúmọ́ ní orílẹ̀-èdè Naijiria. A tẹ ìwé iroyin THISDAY jáde fún ìgbà àkọ́kọ́ ní ọjọ kejìlélógún oṣù kínní, ọdún 1995 (22 January 1995).[1] Olú iléeṣẹ́ rẹ̀ wà ní ilú Apapa, ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Olùdásílẹ̀ ilé-isé ìròyìn náà ni Nduka Obaigbena, òun ni alága ẹgbẹ́ THISDAY media àti ìkànnì ìròyìn ARISE.
THISDAY ni ilé-isé méta fún ìte iroyin, wón wà ní Abuja, Èkó àti Asaba, àwon ni ilé iwe-iroyin tí ó kókó lò inki aláwò ní Nàìjirià [2]
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.