Ìpínlẹ̀ Rivers
Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìpínlẹ̀ Rivers tí a tún mọ̀ bíi Rivers, ni ìkan nínú àwọn ìpínlẹ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà 36. Gẹ́gẹ́ bí dátà ìkanìyàn tó jáde ní ọdún 2006 ṣe fihàn, ìpínlẹ̀ náà ní iye ènìyàn 5,198,716, èyí sọ ọ́ di ìpínlẹ̀ tó ní iye èniyàn púpọ̀jùlọ kẹfà ní Nàìjíríà.[5] Olúìlú àti ìlú tótóbijùlọ rẹ̀ ni Port Harcourt. Ìlú Port Harcourt ní Nàìjíríà gẹ́gẹ́bí gbọ̀ngàn àwọn ilé-iṣẹ́ epo. Ìpínlẹ̀ Rivers jámọ́ Òkun Atlantiki ní gúúsù, ó ní bodè mọ́ àwọn ìpínlẹ̀ Imo and Abia ní àríwá, ìpílẹ̀ Akwa Ibom ní ìlàòrùn, àti àwọn ìpínlẹ̀ Bayelsa àti Delta ní ìwọ̀òrùn. Ìpínlẹ̀ Rivers ní ọ̀pọ̀ ẹ̀yà tí nínú wọn ni: àwọn Ikwerre, àwọn Ijaw, àwọn Ògóni àti àwọn ẹ̀yà púpọ̀ míràn. Orúkọ fún àwọn ará ìpínlẹ̀ yìí ni "Riverians" tàbi "àwọn ará Rivers".[6]
Ìpínlẹ̀ Rivers | ||
---|---|---|
| ||
Nickname(s): | ||
Location of Rivers State in Nigeria | ||
Coordinates: 4°45′N 6°50′E | ||
Orílẹ̀-èdè | Nigeria | |
Geopolitical zone | South South | |
Formation | 27 Oṣù Kàrún 1967 | |
Olúìlú | Port Harcourt | |
LGAs | Àdàkọ:Comma separated entries | |
Government | ||
• Body | Government of Rivers State | |
• Gómìnà[1] | Ezenwo Wike (PDP) | |
• Deputy | Ipalibo Banigo (PDP) | |
• Legislature | House of Assembly | |
Area | ||
• Total | 11,077 km2 (4,277 sq mi) | |
Area rank | 26th | |
Population (2006 Census) | ||
• Total | 5,198,716[2] | |
• Rank | 6th | |
• Density | 635.89/km2 (1,646.9/sq mi) | |
Demonym(s) | Riverian | |
GDP (PPP) | ||
• Year | 2007 | |
• Total | $21.07 billion[3] | |
• Per capita | $3,965[3] | |
Time zone | UTC+01 (WAT) | |
postal code | 500001 | |
ISO 3166 code | NG-RI | |
HDI (2018) | 0.642[4] medium · 6th of 37 | |
Website | riversstate.gov.ng |
Apá inú ìpínlẹ̀ náà jẹ́ ẹgàn tútù olóoru.
Ìpínlẹ̀ Rivers gba orúkọ rè nípase awọn odò ti o la kojá.
Awọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ Rivers jẹ́ mẹ́tàlẹ́lógún tí alága ìbílẹ̀ n se akoso gbogbo ìbílè na:
Orúkọ Ijọba Ìbílẹ̀ | Agbègbè(km2) | Census 2006 population |
Ijoko ìṣàkóso | Postal Code |
Wọ́dù |
---|---|---|---|---|---|
Port Harcourt | 109 | 541,115 | Port Harcourt | 500 | 20 |
Obio-Akpor | 260 | 464,789 | Rumuodumaya | 500 | 17 |
Okrika | 222 | 222,026 | Okrika | 500 | 12 |
Ogu–Bolo | 89 | 74,683 | Ogu | 500 | 12 |
Eleme | 138 | 190,884 | Nchia | 501 | 10 |
Tai | 159 | 117,797 | Sakpenwa | 501 | 10 |
Gokana | 126 | 228,828 | Kpor | 501 | 17 |
Khana | 560 | 294,217 | Bori | 502 | 19 |
Oyigbo | 248 | 122,687 | Afam | 502 | 10 |
Opobo–Nkoro | 130 | 151,511 | Opobo Town | 503 | 11 |
Andoni | 233 | 211,009 | Ngo | 503 | 11 |
Bonny | 642 | 215,358 | Bonny | 503 | 12 |
Degema | 1,011 | 249,773 | Degema | 504 | 17 |
Asari-Toru | 113 | 220,100 | Buguma | 504 | 13 |
Akuku-Toru | 1,443 | 156,006 | Abonnema | 504 | 17 |
Abua–Odual | 704 | 282,988 | Abua | 510 | 13 |
Ahoada West | 403 | 249,425 | Akinima | 510 | 12 |
Ahoada East | 341 | 166,747 | Ahoada | 510 | 13 |
Ogba–Egbema–Ndoni | 969 | 284,010 | Omoku | 510 | 17 |
Emohua | 831 | 201,901 | Emohua | 511 | 14 |
Ikwerre | 655 | 189,726 | Isiokpo | 511 | 13 |
Etche | 805 | 249,454 | Okehi | 512 | 19 |
Omuma | 170 | 100,366 | Eberi | 512 | 10 |
Aboriginal language dialects | ònkà awọn ti wọn n sọ èdè náà |
---|---|
Abua | 25,000 |
Agbirigba | 30 |
Baan | 50,000 |
Biseni | 4,800 |
Defaka | 200 |
Degema | 30,000 |
Ekpeye | 30,000 |
Eleme | 150,000 |
Engenni | 20,000 |
Ijaw | 200,000 |
Ikwerre | 200,000 |
Kalabari | 570,000 |
Kugbo | 2,000 |
Nkoroo | 4,600 |
O’chi’chi’ | — |
Obolo | 250,000 |
Obulom | 3,420 |
Odual | 18,000 |
Ogba | 80,000 |
Ogbogolo | 10,000 |
Ogbronuagum | 12,000 |
Khana | 500,000 |
Okodia | 3,600 |
Oruma | 5,000 |
Tee | 100,000 |
Ukwuani-Aboh-Ndoni | 50,000 |
Awọn orísìrísí èdè tí ó wa ní ìpínlè Rivers nítítò Ijọba ìbílẹ̀ ìpínlè Rivers:[7]
LGA | Languages |
---|---|
Abua-Odual | Kugbo; Odual; Ogbia, Ijaw |
Ahoada East | Igbo, Ekpeye |
Ahoada West | Egenni, ijaw |
Akuku Toru | Kalabari, Bille |
Andoni | Obolo |
Asari-Toru | Kalabari |
Degema | Abua; Degema; Kalabari; Ogbronuagum; Bille |
Bonny | ibani;Ndoki(igbo) |
Eleme | Eleme; Nchia; Odido; Baan |
Emuohua | igbo |
Etche | Obulom-ochichi; Igbo |
Gokana | Baan; Gokana |
Ikwerre | Ikwerre(igbo) |
Khana | Khana, Baan |
Obio-Akpor | Ikwerre (igbo) |
Ogba-Egbema-Ndoni | Igbo |
Ogoni | Kana, Gokana, Tee, Eleme, Baan |
Ogu-Bolo | Kirike |
Ohaji-Egbema Ndoni | Igbo |
Okrika | Kirike, Igbo |
Opobo-Nkoro | Ibani; Igbo, Defaka; ; Nkoroo |
Oyigbo | Igbo, Baan, Kana |
Port Harcourt | obulom; Ikwerre; Kalabari Kirike; Eleme; Kana; Ijaw; Bille; Gokana; Baan; Igbo |
Omumma | Igbo |
Tai | Tee; Baan |
others | Abureni |
Títí di ọdún 1999, ìpínlẹ̀ na ni ile-ẹkọ alakobere bí 2,805 áti ti girama bi 243 tó jẹ́ ti ijọba.
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.