àti Delta ní ìwọ̀òrùn. Ìpínlẹ̀ Rivers ní ọ̀pọ̀ ẹ̀yà tí nínú wọn ni: àwọn Ikwerre, àwọn Ijaw, àwọn Ògóni àti àwọn ẹ̀yà púpọ̀ míràn. Orúkọ fún àwọn ará ìpínlẹ̀
Ìpínlẹ̀ Rivers, Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. ní ọjọ́ keedógún oṣù kínní, Ó jẹ́ ẹ̀yà Ikwerre. Bàbá rẹ̀, Jonathan Okocha, jẹ́ Kọmíṣọ́nà Ọlọ́pá tẹ́lẹ̀ rí, ìyá rẹ̀, Helen