Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun

Ọ̀kan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia

Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣunmap

Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn Ìpínlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun jẹ́ Ìpínlẹ̀ tí ó wà ní àárín gbùngbùn apá Ìwọ̀-Oòrùn Gúúsù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ ni Ìlú Òṣogbo. Ó ní ibodè ní àríwá mọ́ Ipinle Kwara, ní ìlà-oòrùn díẹ̀ mọ́ Ipinle Ekiti àti díẹ̀ mọ́ Ipinle Ondo, ní gúúsù mọ́ Ipinle Ogun àti ní ìwọ̀oòrùn mọ́ Ipinle Oyo. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí ni Gómìnà Ademola Adeleke tí wọn dìbò yàn ni 2022. Gboyega Oyetola sì jẹ́ Gómìnà ìgbà kan rí.[4]

Thumb
Òṣogbo, Osun state
Quick Facts Osun, Country ...
Osun
Thumb
Flag
Official seal of Osun
Seal
Nickname(s): 
Thumb
Location of Osun State in Nigeria
Coordinates: 07°30′N 4°30′E
Country Nigeria
Geopolitical ZoneSouth West
Date created27 August 1991
CapitalOsogbo
Government
  BodyGovernment of Osun State
  GovernorAdemola Adeleke (PDP)
  Deputy GovernorKola Adewusi
  LegislatureOsun State House of Assembly
  SenatorsC: Olubiyi Fadeyi (PDP)
E: Francis Adenigba Fadahunsi (PDP)
W: Kamorudeen Olalere Oyewumi (PDP)
  RepresentativesList
Area
  Total9,251 km2 (3,572 sq mi)
Area rank28th of 36
Population
 (2006 census)
  Total3,416,959[1]
  Rank17th of 36
Demonym(s)Osunian
GDP (PPP)
  Year2021
  Total$14.86 billion[2]
  Per capita$2,691[2]
Time zoneUTC+01 (WAT)
postal code
230001
ISO 3166 codeNG-OS
HDI (2022)0.607[3]
medium · 13th of 37
Websiteosunstate.gov.ng
Close

Ibi tí a ń pè ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lo nii ni wọ́n da sileẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1999. Wọ́ ṣe àfàyọ ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun láti ara Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ wọ́n fún Ìpínlẹ̀ náà ní orúkọ rẹ̀ látara omi Odò Ọ̀ṣun ìyẹn omi tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òrìṣà ilẹ̀ Yorùbá.[5][6]

Orúkọ ìnagijẹ Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ni "ilẹ̀ ọmọlúwàbí".

Ilé ẹ̀kọ́ gíga

Ijọba Ìbílẹ̀

Awọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ Osun jẹ́ ọgbọ̀n. Awọn ná ní:

More information Ijọba Ìbílẹ̀, Olú ilé ...
Ijọba Ìbílẹ̀Olú ilé
AiyedaadeGbongan
AiyedireIle Ogbo
Atakunmosa EastIperindo
Atakunmosa WestOsu
BoluwaduroOtan Ayegbaju
BoripeIragbiji
Ede NorthOja Timi
Ede SouthEde
EgbedoreAwo
EjigboEjigbo
Ife CentralIle-Ife
Ife EastOke-Ogbo
Ife NorthIpetumodu
Ife SouthIfetedo
IfedayoOke-Ila Orangun
IfelodunIkirun
IlaIla Orangun
Ilesa EastIlesa
Ilesa WestEreja Square
IrepodunIlobu
IrewoleIkire
IsokanApomu
IwoIwo
ObokunIbokun
Odo OtinOkuku
Ola OluwaBode Osi
OlorundaIgbonna, Osogbo
OriadeIjebu-Jesa
OroluIfon Osun
OsogboOsogbo
Close

Àwọn èèyàn jànkànjànkàn

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.