Kola Adewusi jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ẹni tí ó jẹ́ ìgbàkejì Gómìnà ìpínlè Osun láti oṣù kọkànlá ọdún 2022.[1] Wọ́n diboyan Adewusi gẹ́gẹ́ bi ìgbàkejì Gomina ìpínlè Osun nínú Ìdìbọ̀ yan Gómìnà ìpínlè Osun tí ó wáyé ní ọdun 2022.[2]
Omoba Kola Adewusi | |
---|---|
Ìgbàkejì Gómìnà ìpínlè Osun | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 27 November 2022 | |
Gómìnà | Ademola Adeleke |
Asíwájú | Benedict Alabi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Peoples Democratic Party |
Àwọn Ìtókasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.