Remove ads
Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia
Ọ̀jọ̀gbọ́n Babagana Umara Zulum tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1969 (August 26th, 1969) jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n àti olóṣèlú ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Borno lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni Gómìnà Ìpínlẹ̀ Born Lọ́wọ́lọ́wọ́. Wọ́n dìbò yàn án lọ́dún 2019 lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́ òṣèlú APC.[1][2]
Babagana Umara Zulum | |
---|---|
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Bọ̀rnó | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 29 May 2019 | |
Asíwájú | Kashim Shettima |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kẹjọ 1969 Mafa |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressive Congress (APC) |
Website | zulum.ng |
Gẹ́gẹ́ bí a ti sọ ṣáájú, wọ́n bí Babagana lọ́jọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1979 ní Ìjọba Ìbílẹ̀ Mafa ní Ìpínlẹ̀ Borno .[3]
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.