![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/4/4a/Susan_Kelechi_Watson.jpg/640px-Susan_Kelechi_Watson.jpg&w=640&q=50)
Susan Kelechi Watson
From Wikipedia, the free encyclopedia
Susan Kelechi Watson tí ó jẹ́ òṣèré Amẹ́ríkà àti ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kọkànlá oṣù Kọkànlá ọdún 1981. Ó di lààmì-laaka látàrí ipa rẹ̀ tí ó ma ń kó ní orí àwọn eré orí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán Louie[1] àti ipa tí ó kó gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtàn Beth Pearson nínú eré This Is Us. Wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ Critics' Choice Television Award for Best Supporting Actress in a Drama Series .
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Ẹ̀kọ́ ...
Susan Kelechi Watson | |
---|---|
![]() Watson at the 2017 Paleyfest | |
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Kọkànlá 1981 (1981-11-11) (ọmọ ọdún 42) Brooklyn, New York, U.S. |
Ẹ̀kọ́ | Howard University (BFA) New York University (MFA) |
Iṣẹ́ | Òṣèré |
Ìgbà iṣẹ́ | 2004–present |
Close