People's Democratic Party

Ẹgbẹ Oṣelu From Wikipedia, the free encyclopedia

People's Democratic Party
Remove ads

Peoples Democratic Party [PDP] (Ẹgbẹ́ Dẹmokrátíkì àwọn Aráàlú) jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n dá ẹgbẹ́ òṣèlú yìí sílẹ̀ lọ́dún 1998.[1] Àwọn ni ọmọ ẹgbẹ́ wọn ṣe ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà títí di ọdún 2015 kí ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress tó gbàjọba àpapọ̀ lọ́wọ́ wọn. Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́, Umaru Musa Yar'Adua àti Goodluck Jonathan ni ẹgbẹ́ yìí jẹ kí ẹgbẹ́ APC tó dà wọ́n lágbo nù lọ́dún 2015, tí Ààrẹ Muhammadu Buhari tí ẹgbẹ́ APC fi wọlé gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ.[2]

Quick Facts Peoples Democratic Party, Chairman ...


Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads