From Wikipedia, the free encyclopedia
Ẹgbẹ́ òṣèlú jẹ́ ẹgbẹ́ tí àwọn òṣèlú tí ìmọ̀, òye àti èròǹgbà jọra dá sílẹ̀ láti díje dupò òṣèlú ní orílẹ̀ èdè tí wọ́n bá lẹ́tọ̀ọ́ rẹ̀ lábẹ́ òfin. Àfojúsùn gbogbo ẹgbẹ́ òṣèlú ni láti jẹ àwọn ipò òṣèlú tí ó bá ṣí sílẹ̀ lórílẹ̀-èdè wọn. [1]
Gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ti Independent National Electoral Commission|INEC, àpapọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú tó wà ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà jẹ́ ókànléláàdọ́rùn-ún (91). [2]
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.