Kárbọ̀nù
From Wikipedia, the free encyclopedia
Kárbọ̀nù (láti Látìnì: carbo "èédú") je ipilese kemika to ni ami-idamo C ati nomba atomu 6. Gẹ́gẹ́ bí ìkan nínú ẹgbẹ́ 14 lórí tábìlì ìdásìkò àwọn ẹ́límẹ̀ntì, ó jẹ́ aláìjẹ́-mẹ́tàlì àti afagbáramẹ́rindìmú—èyí jẹ́ pé ẹ̀lẹ́ktrọ́nù mẹ́rin wà láti dá ìsopọ̀ kẹ́míkà àjọfagbáradìmú. Àwọn ísótòpù kárbọ̀nù mẹ́ta ni wọ́n wà fún ra wọn, 12C àti 13C jẹ́ dídúró, nígbàtí 14C jẹ́ onítítànyindin, tóúntúká díẹ̀díẹ̀ pẹ̀lú àsìkò àbọ̀-ìgbéayé tó tó bíi ọdún 5,730.[11] Kárbọ̀nù ni ìkan nínú àwọn ẹ́límẹ̀ntì díẹ̀ tí wọ́n ti jẹ́ dídámọ̀ láti ìgbà àtijọ́.[12][13]
Àyọkà yìí únfẹ́ ìyílédèdà sí Yorùbá. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ ṣàtúnṣe sí ìyílédèdà |
Graphite (left) and diamond (right), two allotropes of carbon | ||||||||||||||||||||||||||||||
Kárbọ̀nù | ||||||||||||||||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Ìhànsójú | clear (diamond) & black (graphite) | |||||||||||||||||||||||||||||
Ìwúwo átọ̀mù Ar, std(C) | [12.0096, 12.0116] conventional: 12.011 | |||||||||||||||||||||||||||||
Kárbọ̀nù ní orí tábìlì àyè | ||||||||||||||||||||||||||||||
Nọ́mbà átọ̀mù (Z) | 6 | |||||||||||||||||||||||||||||
Ẹgbẹ́ | group 14 (carbon group) | |||||||||||||||||||||||||||||
Àyè | àyè 2 | |||||||||||||||||||||||||||||
Àdìpọ̀ | Àdìpọ̀-p | |||||||||||||||||||||||||||||
Ẹ̀ka ẹ́límẹ́ntì | Reactive nonmetal | |||||||||||||||||||||||||||||
Ìtò ẹ̀lẹ́ktrọ́nù | [He] 2s2 2p2 | |||||||||||||||||||||||||||||
Iye ẹ̀lẹ́ktrọ́nù lórí ìpele kọ̀ọ̀kan | 2, 4 | |||||||||||||||||||||||||||||
Àwọn ohun ìní ara | ||||||||||||||||||||||||||||||
Ìfarahàn at STP | solid | |||||||||||||||||||||||||||||
Sublimation point | 3915 K (3642 °C, 6588 °F) | |||||||||||||||||||||||||||||
Kíki (near r.t.) | amorphous:[1] 1.8–2.1 g/cm3 diamond: 3.515 g/cm3 graphite: 2.267 g/cm3 | |||||||||||||||||||||||||||||
Triple point | 4600 K, 10800[2][3] kPa | |||||||||||||||||||||||||||||
Heat of fusion | 117 (graphite) kJ/mol | |||||||||||||||||||||||||||||
Molar heat capacity | 6.155 (diamond) 8.517 (graphite) J/(mol·K) | |||||||||||||||||||||||||||||
Atomic properties | ||||||||||||||||||||||||||||||
Oxidation states | −4, −3, −2, −1, 0, +1,[4] +2, +3,[5] +4[6] Àdàkọ:Infobox element/symbol-to-oxidation-state/comment | |||||||||||||||||||||||||||||
Electronegativity | Pauling scale: 2.55 | |||||||||||||||||||||||||||||
energies |
| |||||||||||||||||||||||||||||
Covalent radius | 77(sp³), 73(sp²), 69(sp) pm | |||||||||||||||||||||||||||||
Van der Waals radius | 170 pm | |||||||||||||||||||||||||||||
Spectral lines of kárbọ̀nù | ||||||||||||||||||||||||||||||
Other properties | ||||||||||||||||||||||||||||||
Natural occurrence | primordial | |||||||||||||||||||||||||||||
Crystal structure | (diamond, clear) | |||||||||||||||||||||||||||||
Speed of sound thin rod | 18350 (diamond) m/s (at 20 °C) | |||||||||||||||||||||||||||||
Thermal expansion | 0.8 (diamond)[7] µm/(m·K) (at 25 °C) | |||||||||||||||||||||||||||||
Thermal conductivity | 900-2300 (diamond) 119-165 (graphite) W/(m·K) | |||||||||||||||||||||||||||||
Magnetic ordering | diamagnetic[8] | |||||||||||||||||||||||||||||
Young's modulus | 1050 (diamond)[7] GPa | |||||||||||||||||||||||||||||
Shear modulus | 478 (diamond)[7] GPa | |||||||||||||||||||||||||||||
Bulk modulus | 442 (diamond)[7] GPa | |||||||||||||||||||||||||||||
Poisson ratio | 0.1 (diamond)[7] | |||||||||||||||||||||||||||||
Mohs hardness | 10 (diamond) 1-2 (graphite) | |||||||||||||||||||||||||||||
CAS Number | 7440-44-0 | |||||||||||||||||||||||||||||
History | ||||||||||||||||||||||||||||||
Discovery | Egyptians and Sumerians[9] (3750 BC) | |||||||||||||||||||||||||||||
Recognized as an element by | Antoine Lavoisier[10] (1789) | |||||||||||||||||||||||||||||
Main isotopes of kárbọ̀nù | ||||||||||||||||||||||||||||||
| ||||||||||||||||||||||||||||||
Àdàkọ:Category-inline | references |
Orísi àwọn álótrópù kárbọ̀nù lọ́wà tí èyí tó gbajúmọ̀ nínú wọn jẹ́ gráfáìt, díámọ́ndì, àti kárbọ̀nù àìlétòara.[14] Àwọn ìní oníṣeẹ̀dá kárbọ̀nù yàtọ̀ gẹ́gẹ́bí irú álótrópù bá ṣe rí. Fún àpẹrẹ, díámọ́ndì jẹ́ híhannú, nígbàtí gráfáìt jẹ́ dídinú tó sì dúdú. Díámọ́ndì jẹ́ ìkan nínú àwọn èròjà tó le jùlọ, nígbàtí gráfáìt jẹ́ dídẹra dáadáa tó bẹ̀ẹ̀ láti fi kọ ìwé. Díámọ́ndì ní ìgbéwọra oníṣetanná tó kéré gidi, nígbàtí gráfáìt jẹ́ olùgbéwọra tó dára gidigidi. Lábẹ́ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ onídéédé, díámọ́ndì, nánótúbù kárbọ̀nù àti grafínnì ní ìgbéwọra onígbígbóná tó gajùlọ ní àrin àwọn èròjà tí a mọ̀.
Gbogbo àwọn álótrópù kárbọ̀nù jẹ́ aláralíle ní abẹ́ ìṣẹ̀lẹ̀ onídéédé tí gráfáìt jẹ́ irú èyí tó jẹ́ dídúró jùlọ níagbára onítigbígbóná. Wọ́n jẹ́ olódì sí kẹ́míkà bẹ́èsìni wọ́n fẹ́ ìgbónásí gíga láti túndaramọ́ra gan mọ́ ọ́ksíjìn. The most common Ipòàyè ìsọdiọ̀ksídì kárbọ̀nù nínú àwọn àdàpọ̀ aláìníọ́rgánì ni +4, nígbàtí +2 wà nínú mónọ́ksídì kárbọ̀nù àti àwọn metali irekoja karbonili miran. Orisun totobijulo karbonu alainiorgani ni okuta-efun, dolomaiti ati dioksidi karbonu, sugbon opo re tun wa ninu awon ìwalẹ̀ oniorgani èédú, peat, epo petroliomu ati klatarati methani. Karbonu se Carbon forms more adapo ju awon elimenti yiowu lo, bi milionu mewa adapo oniorgani ogidi lo wa titi doni, sibe awon yi ko ju ida die lo ninu gbogbo iye iru adapo karbonu to se e se labe isele onideede.[15]
Karbonu ni elimenti 15k to gbalejulo ni inu iwule Aye, ati elimenti kerin to gbale julo ninu agbala-aye gegebi iye akojo leyin háídrójìn, hílíọ̀mù, ati ọ́ksíjìn. O wa ninu gbogbo iru eda ohun alaye, be sini ninu ara eniyan karbonu ni elimenti keji to gbalejulo gegebi iye akojo (bi 18.5%) leyin oksijin.[16] Igbale yi, lapapo mo ipinsorisirisi awon adapo organiki ati agbara won lati da polimeri ni ibi igbonasi to wopo ni ile Aye, so elimenti yi di ipile kemika gbogbo ohun elemi.