Tábìlì àyè àwọn ẹ́límẹ̀ntì
From Wikipedia, the free encyclopedia
Tábìlì àyè àwọn ẹ́límẹ̀ntì je ona eleto agbehan awon apilese egbo. Bo tile je pe iru tabili yi ti wa tele, eni ti gbogbo eniyan gba pe o da ni onimo khemistry Ararussia Dimitri Mandeleev ni odun 1869. Mandeleev fe tabili yi lati s'afihan ("igba") isele bi a se n da awon apilese mo. Atunse ti bo si iyasile tabili yi, be ni o si ti fe si bi a ba se n seawari awon apilese tuntun be sini a ti se iko apere elero (theoretical model) tuntun la ti se alaye iwuwa egbo.[1]
Tabili igba ti je pataki nisinyi ninu imo eko Khemistry, nipa lati pin si owoowo, la si ona to mogbon wa ati lati safiwe awon orisirisi iru iwa egbo. Be na sini tabili yi n je lilo ninu eko Fisiki, Biology, imoero ati Ileise ero. Tabili ise (standard) isinyi ni 117 apilese ti a le fihan gege bi January 27, 2008 (nigbati apilese 118 ti je imudipo (synthesized) apilese 117 ko ti je be).