![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/0/00/Nigeria_-_Oyo.svg/langyo-640px-Nigeria_-_Oyo.svg.png&w=640&q=50)
Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà / From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìpínlẹ̀ Oyo jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìpínlẹ̀ Mẹ́rìndínlógójì tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ yí wà ní Ìwọ̀ Oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí olú-ìlú rẹ̀ sì fìdí kalẹ̀ sí ìlú Ìbàdàn, tí olú-ìlú rẹ̀ sí jẹ́ ìlú kẹta tí ó lérò púpò julọ ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí o si figbakan je ìlú Kejì tó lérò púpò julọ ní Áfríkà ri. A dá ìpínlè Ọ̀yọ́ sílè ní ọjọ́ kẹta oṣù kejì ọdún 1976. Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ jẹ́ ìpínlè kaarun ti èrò pọ julọ sí ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Quick Facts Country, Date created ...
Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ | |
---|---|
Nickname(s): | |
![]() Location of Ọyọ State in Nigeria | |
Coordinates: 8°00′N 4°00′E[1] | |
Country | ![]() |
Date created | 3 February 1976 |
Capital | Ibadan |
Government | |
• Governor[2] | Oluwaseyi Makinde (PDP) |
• Deputy Governor | Rauf Olaniyan |
• Senators | Abdulfatai Buhari Kola Balogun Teslim Folarin |
• Representatives | List |
Area | |
• Total | 28,454 km2 (10,986 sq mi) |
Population (2006)[3] | |
• Total | 5,580,894[4] |
GDP | |
• Year | 2007 |
• Total | $29.8 billion[5] |
• Per capita | $2,666[5] |
Time zone | UTC+01 (WAT) |
ISO 3166 code | NG-OY |
HDI (2016) | 0.440[6] · 22nd of 36
![]() |
Website | oyostate.gov.ng |
Close
Púpọ̀ nínu àwọn ará ìpínlè Ọ̀yọ́ jẹ́ Yorùbá, ti èdè Yorùbá sì jẹ èdè tí wọ́n n sọ julọ ní ìpínlè náà.
Ṣèyí Mákindé jẹ́ gómìnà ìpínlẹ́ Ọ̀yọ́.