ISO 3166-2:NG
From Wikipedia, the free encyclopedia
ISO 3166-2:NG ni akoole ninu ISO 3166-2, apa opagun ISO 3166 ti International Organization for Standardization (ISO) tejadesiwe to setumo awon amioro fun oruko awon ipinsabe koko ile Naijiria (ti eyi ti amioro ISO 3166-1 alpha-2 je NG).
Lowolowo, agbegbe 1 ati ipinle 36 ni won je fifun ni amioro. Amioro kookan bere pelu NG-, titele pelu leta meji.