Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà jẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin gíga ti ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin oníbínibí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. O ní àwọn asò̀fin 109: ìkọ̀ọ̀kan àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́r̀ndínlógójì jẹ́ pípín sí agbèègbè asòfin mẹta tí wón dìbòyàn asòfin kọ̀ọ̀kan; bé̀ẹ̀ sì ni agbè̀gbè olúìlú ìjọba àpapọ̀ náà dìbòyàn asòfin kan pééré.