Emily Nkanga
From Wikipedia, the free encyclopedia
Emily Nkanga jẹ́ ayàwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan, ó tún ń ṣe fíìmù jáde. Nkanga gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn olórin bi Koker, Aramide, Boj, Olamide, Jidenna, Not3s,[1] Mr Eazi, Mayorkun, Adekunle Gold, Sarz, òṣèré Adesola Osakalumi, agbábọ́ọ̀lù Tammy Abraham àti Femi Kuti.[2] Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àwòrán Nkanga jẹ́ nípa àwọn ènìyàn tí wón ti pàdánù ilé àti ọ̀nà wọn ní àríwá Nàìjíríà nítorí ogun Boko Haram.[3]
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Iṣẹ́ ...
Emily Nkanga | |
---|---|
Emily Nkanga ní London ní ọdún 2017 | |
Ọjọ́ìbí | Emily Oluwatobi Nkanga 21 Oṣù Kàrún 1995 (1995-05-21) (ọmọ ọdún 28) Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Ayàwòrán |
Ìgbà iṣẹ́ | 2012 títí di ìsinsìnyí |
Website | emilynkanga.com |
Close