Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan Brítánì Olókìkí àti Írẹ́lándì Apáàríwá ti a mo si Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan, UK tabi Britani jẹ́ orílẹ̀-èdè ní Europe. Nínú bodè rẹ̀ ni a ti rí erékùsù Brítánì Olókìkí, apá ìlàoòrùn-àríwá erékùsù Irẹlandi àti ọ̀pọ̀ àwọn erékùsù kékéèké. Irẹlandi Apáàríwá nìkan ni apá Ilẹ̀ọba Ìsọ̀kan tó ní bodè mọ́ oríilẹ̀ pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Irẹlandi.
Quick Facts Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan Brítánì Olókìkí àti Írẹ́lándì ApáàríwáUnited Kingdom of Great Britain and Northern Ireland, Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...
Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan Brítánì Olókìkí àti Írẹ́lándì Apáàríwá United Kingdom of Great Britain and Northern Ireland | |
---|---|
Motto: ["Dieu et mon droit"] error: {{lang}}: text has italic markup (help) (French) "God and my right" | |
Ibùdó ilẹ̀ Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan (dark green) – on the European continent (light green & dark grey) | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | London |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | English |
Lílò regional languages | Welsh, Irish, Ulster Scots, Scots, Scottish Gaelic, Cornish |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2001) | 92.1% White, 4.00% South Asian, 2.00% Black, 1.20% Mixed Race, 0.80% East Asian and Other |
Orúkọ aráàlú | British, Briton |
Ìjọba | Parliamentary system and Constitutional monarchy |
• Monarch | Charles III |
• Prime Minister | Keir Starmer |
Aṣòfin | Parliament |
• Ilé Aṣòfin Àgbà | House of Lords |
• Ilé Aṣòfin Kéreré | House of Commons |
Formation | |
• Acts of Union | 1 May 1707 |
• Act of Union | 1 January 1801 |
• Anglo-Irish Treaty | 12 April 1922 |
Ìtóbi | |
• Total | 244,820 km2 (94,530 sq mi) (79th) |
• Omi (%) | 1.34 |
Alábùgbé | |
• mid-2006 estimate | 60,587,300[1] (22nd) |
• 2001 census | 58,789,194[2] |
• Ìdìmọ́ra | 246/km2 (637.1/sq mi) (48th) |
GDP (PPP) | 2006 estimate |
• Total | US$2.270 trillion (6th) |
• Per capita | US$37,328 (13th) |
GDP (nominal) | 2007 estimate |
• Total | $2.772 trillion (5th) |
• Per capita | US$45,845 (9th) |
Gini (2005) | 34[3] Error: Invalid Gini value |
HDI (2005) | ▲ 0.946 Error: Invalid HDI value · 16th |
Owóníná | Pound sterling (£) (GBP) |
Ibi àkókò | UTC+0 (GMT) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+1 (BST) |
Àmì tẹlifóònù | 44 |
Internet TLD | .uk |
Close