Ìrágbìjí
From Wikipedia, the free encyclopedia
Iragbiji (tí a tún mọ̀ sí Ira-gba-iji) jẹ́ ìlú kan, àti olú ìlú àgbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Boripe ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Nàìjíríà, nítòsí Ikirun. Àwọn ọmọ Yorùbá ló ń gbé àgbègbè náà.[1] Iye àwọn ènìyàn tó ń gbé níbẹ̀ wọ 164,172.[2]