From Wikipedia, the free encyclopedia
Òòrùn ni ìràwọ̀ tó wà láàárín ètò òòrùn. Ilẹ̀-ayé àti àwọn ohun mìíràn (àwọn pílánẹ́ẹ̀tì yoku, oníràwọ̀, olókùúta, òkúta iná àti eruku) wọ́n ń yípo òòrùn, tó ṣe fúnra rẹ̀ nìkan ni ìtóbi 99.8% gbogbo Ètò Òòrùn. Okun láti inú òòrùn gẹ́gẹ́ bíi ooruntitan ń pèsè fún àwọn ohun ẹlẹ́mìí lọ́nà tí a mọ̀ sí ikommolejo (photosynthesis), bẹ́ẹ̀ ni òòrùn ló ń sọ bí ìgbà àti ojú-ọjọ́ ṣe ń rí.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Observation data | |
---|---|
Mean distance from Earth |
1.496×108 km 8 min 19 s at light speed |
Visual brightness (V) | −26.74 [1] |
Absolute magnitude | 4.83 [1] |
Spectral classification | G2V |
Metallicity | Z = 0.0122[2] |
Angular size | 31.6′ – 32.7′ [3] |
Adjectives | solar |
Orbital characteristics | |
Mean distance from Milky Way core |
~2.5×1017 km 26,000 light-years |
Galactic period | (2.25–2.50) × 108 a |
Velocity | ~220 km/s (orbit around the center of the Galaxy) ~20 km/s (relative to average velocity of other stars in stellar neighborhood) ~370 km/s[4] (relative to the cosmic microwave background) |
Physical characteristics | |
Mean diameter | 1.392×106 km [1] 109 × Earth |
Equatorial radius | 6.955×105 km [5] 109 × Earth[5] |
Equatorial circumference | 4.379×106 km [5] 109 × Earth[5] |
Flattening | 9×10−6 |
Surface area | 6.0877×1012 km2 [5] 11,990 × Earth[5] |
Volume | 1.412×1018 km3 [5] 1,300,000 × Earth |
Mass | 1.9891×1030 kg[1] 333,000 × Earth[1] |
Average density | 1.408×103 kg/m3 [1][5][6] |
Density | Center (model): 1.622×105 kg/m3 [1] Lower photosphere: 2×10−4 kg/m3 Lower chromosphere: 5×10−6 kg/m3 Corona (avg.): 1×10−12 kg/m3 [7] |
Equatorial surface gravity | 274.0 m/s2 [1] 27.94 g 28 × Earth[5] |
Escape velocity (from the surface) |
617.7 km/s [5] 55 × Earth[5] |
Temperature | Center (modeled): ~1.57×107 K [1] Photosphere (effective): 5,778 K [1] Corona: ~5×106 K |
Luminosity (Lsol) | 3.846×1026 W [1] ~3.75×1028 lm ~98 lm/W efficacy |
Mean Intensity (Isol) | 2.009×107 W·m−2·sr−1 |
Rotation characteristics | |
Obliquity | 7.25° [1] (to the ecliptic) 67.23° (to the galactic plane) |
Right ascension of North pole[8] |
286.13° 19h 4min 30s |
Declination of North pole |
+63.87° 63°52' North |
Sidereal rotation period (at equator) |
25.05 days [1] |
(at 16° latitude) | 25.38 days [1] 25d 9h 7min 12s [8] |
(at poles) | 34.4 days [1] |
Rotation velocity (at equator) |
7.189×103 km/h [5] |
Photospheric composition (by mass) | |
Hydrogen | 73.46%[9] |
Helium | 24.85% |
Oxygen | 0.77% |
Carbon | 0.29% |
Iron | 0.16% |
Neon | 0.12% |
Nitrogen | 0.09% |
Silicon | 0.07% |
Magnesium | 0.05% |
Sulfur | 0.04% |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.