Ayé, tàbí Ilé-ayé ni ile asan ile to kun fun wahala ati ipayinkeke ile aye le gannn puli walahi afi ki eledumare oba saanu wa ni faaaaa. Bakan naa naijiria ti oje ilu ti awa yii ko rogba rara wahala lotun losi, kosi epo kosi owo kosi ounje gbogbo wahala yen to suwa bayi oooo sii jẹ́ pílánẹ́ẹ̀tì kẹta sí òòrùn, ó sì jẹ́ èyí tí ó tóbi jùlo nínú àwọn pílánẹ́ẹ̀tì tí wọ́n ní ilẹ̀ tí ó ṣe é tẹ̀. 🜨

Quick Facts Ìfúnlọ́rúkọ, Ìpolongo ...
Ayé  🜨
Thumb
"The Blue Marble" photograph of Earth,
taken from Apollo 17
Ìfúnlọ́rúkọ
Ìpolongo Gbígbọ́i /ˈa/
Alápèjúwe earthly, tellurian, telluric, terran, terrestrial.
Àwọn ìhùwà ìgbàyípo
Àsìkò J2000.0[note 1]
Aphelion152,098,232 km
1.01671388 AU[note 2]
Perihelion 147,098,290 km
0.98329134 AU[note 2]
Semi-major axis 149,598,261 km
1.00000261 AU[1]
Eccentricity 0.01671123[1]
Àsìkò ìgbàyípo 365.256363004 days[2]
1.000017421 yr
Average orbital speed 29.78 km/s[3]
107,200 km/h
Mean anomaly 357.51716°[3]
Inclination 7.155° to Sun's equator
1.57869°[4] to invariable plane
Longitude of ascending node 348.73936°[3][note 3]
Argument of perihelion 114.20783°[3][note 4]
Satellites 1 (the Òṣùpá)
Àwọn ìhùwà àdánidá
Iyeìdáméjì ìfẹ̀kiri 6,371.0 km[5]
Ìfẹ̀kiri alágedeméjì 6,378.1 km[6]
Ìfẹ̀kiri olóòpó 6,356.8 km[7]
Flattening 0.0033528[6]
Circumference 40,075.16 km (equatorial)[8]
40,008.00 km (meridional)[8]
Ààlà ojúde 510,072,000 km2[9][10][note 5]

148,940,000 km2 land (29.2 %)

361,132,000 km2 water (70.8 %)
Ìpọ̀sí 1.08321 × 1012 km3[3]
Àkójọ 5.9736 × 1024 kg[3]
Iyeìdáméjì ìṣùpọ̀ 5.515 g/cm3[3]
Equatorial surface gravity9.780327 m/s2[11]
0.99732 g
Escape velocity11.186 km/s[3]
Sidereal rotation
period
0.99726968 d[12]
23h 56m 4.100s
Equatorial rotation velocity 1,674.4 km/h (465.1 m/s)[13]
Axial tilt 23°26'21".4119[2]
Albedo0.367 (geometric)[3]
0.306 (Bond)[3]
Ìgbónásí ojúde
   Kelvin
   Celsius
minmeanmax
184 K[14]287.2 K[15]331 K[16]
-89.2 °C14 °C57.8 °C
Afẹ́fẹ́àyíká
Ìfúnpá ojúde 101.325 kPa (MSL)
Ìkósínú 78.08% nitrogen (N2)[3]
20.95% oxygen (O2)
0.93% argon
0.038% carbon dioxide
About 1% water vapor (varies with climate)
Close

Ilé-ayé jé pílánẹ́ẹ̀tì àkọ́kọ́ tí ó ní omi tó ń sàn ní orí rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ sìni Ilé-ayé nìkan ni pílánẹ́ẹ̀tì tí iwadi fidi rẹ mulẹ[17] wipe o ni ojú-òrun (atmosphere) ti o jẹ́ kìkì nitrogen àti oxygen tí ó ń dà àbò bo ilé-ayé lọ́wọ́ àtaǹgbóná (radiation) tó léwu sí ènìyàn. Bákan náà ojú-òrun kò gba àwọn yanrìn-òrun láàyè láti jábọ́ sí ilé-ayé nípa sísun wọ́n níná kí wọ́n ó tó lè jábọ́ sí ilé-ayé. [7]

Thumb
Òṣùpá ati Ilé-ayé

Àwọn Ìtókasí

Wikiwand in your browser!

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.

Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.