Yemi Blaq
From Wikipedia, the free encyclopedia
Yẹmí Blaq tí orúkọ ibí rẹ̀ jẹ́ Fọláyẹmí Ọlátúnjí jẹ́ Òṣèré fíìmù Nàìjíríà, Olùdá Fíìmù, Akọ-orin àti Módẹ́ẹ̀lì.[1][2][3]
Yẹmí Blaq | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ìpínlẹ̀ Òǹdó, Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Film actor |
Awards | Best Actor in a Leading Role, Africa Magic Viewer's Choice Awards |
Ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ Ayé àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀
Yẹmí ọ̀gbẹni Ọlátúnjí Blaq bí ní ìpínlẹ̀ Òǹdó, Nàìjíríà. Yẹmí Blaq dàgbà sí ìpínlẹ̀ Èkó níbi tó ti lọ àti parí ilé-ìwé pámárìlì àti ilé -ìwé Fáṣítì. Ó lọ sí Adéyẹmí Demonstration Secondary school ní Òǹdó, Ìpínlẹ̀ Òǹdó àti wí pé òun ló kọ́kọ́ jẹ́ hẹ́ẹ́dí bọyì fún ilé-ìwé náà. Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní máa kópa nínu eré ṣíṣe nígbà tó wà ní ilé-ìwé gíga títí di àsìkò.
Iṣẹ́ Ààyò
Yẹmí Blaq bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ààyò rẹ̀ lórí Nólíwoòdì ní ọdún 2005. Ó ti fọwọ́bọ̀wé pẹ̀lú àwọn Actors Guild of Nigeria nígbà díẹ̀ sẹ́yìn láti di Òṣèré. Eré àkọ́kọ́ tó sọ ọ́ di ènìyàn tó gbajúmọ̀ Lost of Lust níbi tó ti seré lẹ́gẹ̀ẹ́kẹ̀gbẹ́ pẹ̀lú Mercy Johnson. Lẹ́yìn eré àkọ́kọ́ yìí, àwọn Òṣèré ẹgbẹ́ rẹ̀ ti ń wa kó bá àwọn ṣeré àti wí pé àti ìgbà náà ló tí ń ṣeré.[4]
Àwọn eré tó ti kópa
- The Good Samaritan 2 (2004)
- Without Shame (2005)
- Lost to Lust (2005)
- 11 Days 11 Nights 2 (2005)
- Traumatised (2006)
- Total Control (2006)
- Sting (2006)
- Mamush (2006)
- Desperate Ambition (2006)
- Sinking Sands (2011)
- Strive (2013)
- President for a Day (2014)
- The Last 3 Digits (2015)
- Cultural Clash (2019)
- 12 Noon (completed)
- Shadow Parties (2020)
Àwọn oyè
Year | Award | Category | Nominated Work | Result | Refs |
---|---|---|---|---|---|
Africa Magic Viewer's Choice Awards | Best Actor in a Leading Role | My Idol (Film) | Gbàá | [5] | |
2018 | Best of Nollywood Awards | Best Kiss in a Movie | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [6] | |
Golden Movie Awards | Golden Supporting Actor | Nominated | [7] |
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.