From Wikipedia, the free encyclopedia
Wọlé Òjó ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹfà oṣù Kẹfà, ọdún 19884.(bí 6 Okudu 1984). Ójẹ́ òṣèré jẹ oṣere orí ìtàgé ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó dìlú mọ̀ọ́ká ní inú iṣẹ́ sinimá nílẹ̀ Nàìjíríà ní ọdún 2009, lẹ́yìn tí ó gbé ipò kẹ́rin nínú ìdíje Amstel Malta Box Office.
Wole Ojo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 6 Oṣù Kẹfà 1984 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Actor |
Notable work | The Child |
Ó gba oyè ìmọ̀ ẹ̀kọ́ nínú iṣẹ́ Àtinúdá (Creative Arts) láti ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì ìlú Èkó.
Ọdún | Fíìmù | Ojúṣe | Ọ̀rọ̀ |
---|---|---|---|
2011 | Maami | Kashimawo | Eré-oníṣe |
2012 | When Fishes Drown | Tony | Eré-oníṣe |
2013 | Conversations at Dinner | Chidi Obi | Eré-oníṣe |
2014 | Umbara Point | Jelani | Thriller |
Perfect Union | Steve Kadiri | Eré-oníṣe | |
Brave | Nathan Doga | Fíìmù kékeré | |
2015 | The MatchMaker | Bryan | fíìmù ajẹmọ́-ìfẹ́ |
Out of Luck | Seun | Eré-oníṣe | |
7 Inch Curve | Kamani | Eré-oníṣe | |
2016 | Beyond Blood[1] | fíìmù ajẹmọ́-ìfẹ́ | |
Entreat[2] | Segun Adeoye | fíìmù ajẹmọ́-ìfẹ́ | |
2018 | Bachelor's Eve[3] | Uche | Eré-oníṣe |
Ọdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Olùgbà | Èsì |
---|---|---|---|---|
2010 | 6th Africa Movie Academy Awards[4] | Most Promising Actor | The Child | Wọ́n pèé |
2014 | City People Entertainment Awards[5] | Best New Actor (Yoruba) | Wọ́n pèé | |
2013 | 2013 Nollywood Movies Awards[6] | Best Actor (Indigenous) | Maami | Wọ́n pèé |
2015 | 2015 Africa Magic Viewers Choice Awards[7] | Best Actor in a Drama | Brave | Wọ́n pèé |
2015 Nigeria Entertainment Awards[8] | Actor of the Year (Nollywood) | Brave | Wọ́n pèé | |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.