Yunifásítí ti ìjọba àpapọ̀ ti ìpínlẹ̀ Èkó, ní Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Yunifásítì ìlú Èkó (University of Lagos tàbí UNILAG) jé fásitì ìjọba àpapò ni Naijiria tó bùdó si ilu Èkó.
Yunifásítì ìlú Èkó University of Lagos | |
---|---|
Motto | In deed and in truth. |
Established | 1962 |
Type | Public |
President | Prof Tolu Olukayode Odugbemi |
Location | Lagos, Nigeria |
Campus | Urban |
Website | www.unilag.edu.ng |
A dá UNILAG silẹ ni ọdún 1962, ọdún méjì lẹ́yìn òmìnira Naijiria independence of Nigeria láti ọwó àwọn Britain. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn yunifásítì márùn-ún tí a dá lè ní orílè-èdè Nàìjíríà, tí a mò sí "first generation universities".[1][2] Eni Njoku ni a yàn gẹ́gẹ́ bí alákòóso àkọ́kọ́ ní yunifásítì ní ọdún 1962, èyí tí ọ́ ṣe títí di ọdún 1965 tí a sì ni ipò pada pẹ̀lú Saburi Biobaku. síbẹ̀síbẹ̀, nítorí àwọn àríyànjiyàn nípa bí a sè yàn sí ipò , ọ̀gbẹ́ni Kayode Adams gún Saburi pa , akẹ́kọ̀ọ́ tí ó gbàgbọ́ pé ááyan Saburi nítorí ẹyà ti ọ sí bójú mu.[3]
Láti ọdún 2017 [4] Títí di ojo òní , igbakeji olórí ni ọ̀jọ̀gbọ́n Oluwatoyin Ogundipe.ni ọdún 2019, Telifísàn BBC sọ̀rọ̀ nípa "female reporters were sexually harassed, propositioned and put under pressure by senior lecturers at the institutions – all the while wearing secret cameras".[5][6] yíyọ àwọn obìrin oníròyìn lẹ́nu lórí ìbálópọ̀ àti ìfúgunmọ́ láti ọwọ́ àwọn olùkọ́ àgbà ní yunifásítì ní àwọn ilé-ìwé - láti ìgbà yìí wa ni wọ́n gbé kámẹ́rà pamọ́ sára.
Yunifásítì tí gbé oríṣiríṣi ọ̀jọ̀gbọ́n tí ó yanrantí jáde nínú ìmọ̀ síyẹ́ǹsì, òṣèlú, amòfin, àwọn oníṣòwò ńlá , òǹkọ̀wé, àwọn eléré ìdárayá, àwọn ọba, ìmọ̀-ẹ̀rọ,ti ìlú Nàìjíríà àwọn olóye gbogbo , àti àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ìwe mìíràn pẹ̀lú . Ni oṣù kẹsàn-án ọdún 2020, ọ̀kan lára àwọn nobel laureate àti ọ̀kan lára Pulitzer prize laureate ni wọ́n kà gẹ́gẹ́ bí i ọmọ ilẹ́ ìwé yunifásítì ìlú Èkó , ọmọ ilẹ́ ìwé, olùkọ́, tàbí òṣìṣẹ́.
Láti jẹ ile ẹkọ tó Dára jù lọ nínú títà yo imo, ìwà ati rí ran àwon eniyan lowo.[7]
Láti ṣe ibùgbé tí ó dára fún ẹ̀kó, ìwé kika, Ìwádìí àti ìdàgbàsókè, níbití òṣìṣẹ́ àti akẹ́kọ̀ọ́ yóò ní Àjosepò tó dán mọ́rán láti kojú ẹlẹ́gbẹ́ won ni gbogbo àgbáyé [8]
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.