Olóṣèlú Nàìjíríà (1939-2015) From Wikipedia, the free encyclopedia
Uche Chukwumerije (Oṣù kọkànlá Ọdún 1939 sí Ọjọ́ Ọkàndínlógún Oṣù kẹrin Ọdún 2015) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àríwá Abia, ìpínlẹ̀ Abia ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Oṣù kẹrin Ọdún 2011 sí Oṣù kejìlá Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1]
Uche Chukwumerije | |
---|---|
Aṣojú àríwá Abia ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà | |
In office Ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 2003 – Ọjọ́ ọ̀kàndínlógún Oṣù kẹrin Ọdún 2015 | |
Asíwájú | Ike Nwachukwu |
Arọ́pò | TBD |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Oṣù kọkànlá ọdún 1939 ìpínlẹ̀ Abia, Nàìjíríà |
Aláìsí | 2015 Abuja, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | PDP |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.