Olóṣèlú àti ológun ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Chukwuemeka Odumegwu-Ojukwu (a bíi ní ọjọ́ kẹrin oṣù kọkànlá ọdún 1933[1] - ó sì kú ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún 2001)jẹ́ ológun àti òṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ [2]. Ó fìgbà kan jẹ Gómìnà ológun apá àríwá Nàìjíríà lọ́dún 1966. Oun ló ṣe égbátẹrù ogun abẹ́lé Biafra fi tako ìjọba orile-ede Nàìjíríà lọ́dún 1967 sí 1970[3].
General C. Odumegwu Ojukwu | |
---|---|
President of Biafra | |
In office 30 May 1967 – 8 January 1970 | |
Vice President | Philip Effiong |
Asíwájú | Position created |
Arọ́pò | Philip Effiong |
Constituency | Biafra |
Governor of Eastern Region, Nigeria | |
In office 19 January 1966 – 27 May 1967 | |
Asíwájú | Francis Akanu Ibiam |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Zungeru, Nigeria | 4 Oṣù Kọkànlá 1933
Aláìsí | 26 November 2011 ọdún 78) United Kingdom | (ọmọ
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Nigerian Military, Biafra military, later APGA |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Bianca Ojukwu |
Alma mater | Lincoln College, Oxford University |
Profession | Soldier, politician |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.