From Wikipedia, the free encyclopedia
Nigerian Defence Academy tabi Ile-eko Oro Abo Naijiria ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fun awon omo-ologun to wa ni ilu Kaduna[1][2]. Akoko ikẹẹkọ Ile-eko Oro Abo Naijiria jẹ ọdun marun (Ọdun mẹrin fun ti akadẹmi ati ọdun kan fun ti ologun)[3].
Ile-ẹkọ ọrọ abo Naigiria ni a dasilẹ ni óṣu February, ọdun 1964[4] gẹgẹbi atunṣè ti ilẹ british lati ṣè akoso ikẹẹkọ ti ólógun collẹgi RMFTC ti wọn pada sọ ni collẹgi ikẹẹkọ ologun ti ilẹ Naigiria ta mọsi NMTC ni ọjọ ti órilẹ ede naa gba óminira. Ilẹ ẹ̀kọ ologun kọ awọn óṣiṣè ti ologun, awọn ologun to mojuto omi ati awọn ologun to mojuto oke ofurufu[5][6].
Yara Ikawe Ilẹ ẹkọ ọrọ abo jẹ ọkan gbogi fun ikọni ati ikẹẹkọ ti ologun. Yara Ikawe ti akadẹmi naa ni a da silẹ̀ ni ọdun 1963 lati gbe ikẹẹkọ larugẹ[7]. Oluṣakoso yara ikawe naa lọwọ ni Umar Lawal[8].
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.