Mountain Top University jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga aládáni ní Makogi Oba, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà, tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 2015. Ilé-ẹ̀kọ́ náà ni wọ́n mọ̀ fún ìfọkànsìn pẹ̀lú ìwà rere àti ìkànsí àwọn iṣẹ́ ẹ̀mi, àti ẹ̀ka òrin tó wà lárin àwọn tó dára jùlọ ní orílẹ̀-èdè náà.[1][2] Ìjọ Pentecostal Mountain of Fire and Miracles Ministries ní òdá ilé-ẹ̀kọ́ náà sílẹ̀. Olùkọ àgbà Daniel Kolawole Olukoya, tó jẹ́ olùdásílẹ̀ àti gbogbogbo alága ti MFM Ministries, ló dá ilé-ẹ̀kọ́ náà sílẹ̀.

Quick Facts Motto, Established ...
Mountain Top University
Mountain Top University Main Entrance.jpg
MottoEmpowered To Excel
Established2015
TypePrivate
ChancellorProf Daniel Kolawole Olukoya
Vice-ChancellorProf. Elijah Ayolabi
Students1800(Undergraduate)
LocationKm 12 Lagos/Ibadan Expressway, Ogun State, Nigeria
Websitemtu.edu.ng
Close

Àwọn ẹ̀ka àti ètò ẹ̀ko

Mountain top University ní ẹ̀ka méjì (2 colleges) àti ètò ẹ̀kọ́ márùndínlógún (15 departments). Àwọn ní:[3]

  • Ẹ̀ka Basic and Applied Sciences
  • Ẹ̀ka Humanities, management and Social Sciences

Àwọn ètò ẹ̀kọ́

Ìpele àti ipò

Ní ọdún 2023, Mountain Top University jẹ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga tó wa ní ipò kẹ̀tàdínlógórùn (97) ní Nàìjíríà àti ilé ẹ̀kọ́ gíga aládáni tó wa ní ipò 11,256 ní gbogbo ayé.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí

Àwọn àtẹ̀jade

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.