Korede Bello

From Wikipedia, the free encyclopedia

Korede Bello

Korede Bello (tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n, oṣù kejì, ọdún 1996) ọ̀kọrin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti akọrin sílẹ̀.[1] Ó tẹwọ́bọ̀wé pẹ̀lú Mavin Records ní ọdún 2014. Orin rẹ̀ "Godwin" ló mu bọ́ sí gbangba.[2]

Quick Facts Background information, Ọjọ́ìbí ...
Korede Bello
Thumb
Background information
Ọjọ́ìbí29 Oṣù Kejì 1996 (1996-02-29) (ọmọ ọdún 29)
Lagos State, Nigeria
Irú orinÀdàkọ:Csv
Occupation(s)Àdàkọ:Csv
Years active2009–present
LabelsMavin Records
Associated acts
Websitekoredebello.com
Close

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé

Korede (Èyí tí ó túǹmọ́ Ko Ire Wá) jẹ́ ọmọ tí tí wọ́n bí sí ìlú Èkó, ibè náà ló tí ká ìwé alákọ̀bẹrẹ̀ àti ilé ìwé Sẹ́kọ́ńdìrí. Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣeré ìdárayá nígbà tí ó wá ní ọmọ ọdún Méje, orúkọ rẹ ní gbà náà sì ń jẹ́ "African Prince"

Iṣẹ́

Nígbà tí ó wá ní ilé ìwé alákọ̀bẹrẹ̀, Korede Bello kọ Orin àkọkọ́ lẹ́yìn tí ó dá egbé kàn sílè pẹlú ọ̀rẹ rẹ̀.[3] Ó mú iṣẹ orin lokunkundu lẹyìn tí ó kó àwọn Orin nínú Studio [4] Ni ilé ìwé Gírámà, o ṣé àwó orin tí óò pé àkọlé rẹ̀ ni 'FOREVER' èyí tí ó ẹ́ akọkọ. O tẹsiwaju nínú èkó rè láti lọ mọ nípa Ìmọ̀ ibi-ibaraẹnisọrọ (Mass communication), ọ sí ní Certificate Higher National Diploma. Korede Bello jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ tí iléesẹ́ tí Institute Of Information Management.[5][6]

Ìsowọ́pọ̀ pẹ̀lú Mavin Records

Lẹ́yìn tí ó Àwó àkọkọ́ jáde, èyí tó o gbà oríyìn tí odará, ní ọgá rẹ Casmir Uwaegbute mú hàn ( Don Jazzy) èyí tí wọ́n jọ gbìmọ kọ orin mìíràn, tí inú Don Jazzy sí dùn sí.[7] Ni ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n, oṣù Kejì ọdún 2014, ni ó wọ Mavins Record lábẹ́ èyí tí o tún gbé àwọn orin tó jẹ́ gbajùmọ̀ bíi " African Princess" àti " Godwin"[8] Lówó lọwọ́ ó ń ṣe àkọ́kọ́ ìṣiṣẹ́ Album, èyí tí ó sí fí ÀṢÀ àti 2face idibia ṣe àwọn àwòrán ẹnití tí ó ń rí ìmísí láti ará orin tí wọ́n tí kò sẹ́yìn.[9]

Iṣẹ Ọmọnìyàn

Kóredé Bello ti ṣe awọn oríṣiríṣi iṣẹ Ọmọnìyàn bí "Project Pink Blue walk" fún ìmọ lori Àrùn Jẹjẹrẹ (Cancer) ni ìlú Abuja, ni ọdún 2015 . [10][11][12] àti 2017

Àtojọ àwọn orin rè

Àwo-orin ti studio

  • Belloved (2017)

Singles

More information Title, Year ...
Title Year Release date
"African Princess" 2014 28 February 2014
"Dorobucci"
(with Don Jazzy, Tiwa Savage, Dr SID, D'Prince, Reekado Banks and Di'Ja)
1 May 2014
"Adaobi"
(with Don Jazzy, Reekado Banks and Di'Ja)
27 May 2014
"Cold Outside" 15 August 2014
"Looku Looku"
(with Don Jazzy, Tiwa Savage, Dr SID, D'Prince, Reekado Banks and Di'Ja)
31 October 2014
"Jingle Bell" 25 December 2014
"Godwin"
2015 28 January 2015
"Jantamanta"
(with Don Jazzy Tiwa Savage, Dr SID, D'Prince, Reekado Banks and Di'Ja)
27 October 2015
"Romantic"
(with Tiwa Savage)
December 2015
"Mungo Park" 2016 7 May 2016
"One & Only" 26 May 2016
"Do Like That" 13 September 2016
"Butterfly" 2017 17 May 2017
"My People" 1 September 2017
"Melanin Popping" 2018 18 January 2018
"Work it" 1 April 2018
"So te" 7 May 2018
"2geda" 22 May 2018
"Champion" 29 September 2018
"Bless Me" 30 September 2018
"Mr. Vendor" 2019 26 April 2019
"Sun Momi (Only You)" 2020 12 February 2020
Close

Àwọn Àmì Ẹ̀yẹ

More information Year, Award ceremony ...
Year Award ceremony Prize Recipient/Nominated work Result Ref
2014 Nigeria Teen Choice Awards 2014 Most Promising Music Act To Watch Himself Gbàá [13]
2015 4th Annual Golden Icons Academy Movie Awards Best Song of the Year "Godwin" Gbàá [14]
2015 Nigeria Entertainment Awards Hottest Single of The Year Wọ́n pèé [15]
Best New Act Himself Wọ́n pèé [15]
2016 The Headies 2015 Best Pop Single "Godwin" Gbàá [16]
Song of The Year Wọ́n pèé [17]
Next Rated Himself Wọ́n pèé [17]
2016 City People Entertainment Awards Pop Artiste of the Year Himself Gbàá [18]
2016 Nigeria Entertainment Awards Best Collaboration "Romantic" (featuring Tiwa Savage) Wọ́n pèé [19]
9th Nigeria Music Video Awards Best Contemporary Afro Video "Godwin" Gbàá [20]
Close

Àwọn ìtọkasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.