Dosu Joseph
Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Joseph Dosu tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọ̀kàndínlógún oṣù kẹfà ọdún 1973 (19th June 1973) ní ìlú Àbújá, Olú ìlú orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Àgbádárìgì ní ìpínlẹ̀ Èkó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1] [2] Dosu Joseph wà lára àwọn ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Òlíḿpííkì fún orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n gba àmìn ẹ̀yẹ wúrà ní Atlanta lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà lọ́dún 1996. [3]
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Joseph Dosu | ||
Ọjọ́ ìbí | 19 Oṣù Kẹfà 1973 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Abuja, Nigeria | ||
Ìga | 6 ft 4 in (1.93 m) | ||
Playing position | Goalkeeper | ||
Club information | |||
Current club | Westerlo Football Academy (Head coach) | ||
Youth career | |||
until 1990 | Julius Berger | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
1991–1996 | Julius Berger | ||
1996–1998 | Reggiana | 0 | (0) |
National team | |||
1996–1997 | Nigeria | 3 | (0) |
Teams managed | |||
2009– | Westerlo Football Academy | ||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki | |||
Adíje fún Nàìjíríà | |||
---|---|---|---|
Men's Football | |||
Wúrà | 1996 Atlanta | Team Competition |
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.