Open Australia je ikan ninu awon idije Grand Slam merin to uwaye ninu ere-idaraya alagbase Tenis. O unwaye lodoodun ni Australia labe ase Tennis Australia, teletele tounje Egbe Ajose Tenis Australia (Lawn Tennis Association of Australia, LTAA) beesini idije akoko re waye lori papa isere kriket ni Melbourne ni 1905. Loni won unpe ibe ni Albert Reserve Tennis Centre.[2]

Quick Facts Official website, Grand Slam ...
Open Austrálíà
Australian Open
Official website
IbùdóMelbourne
 Australia
PápáMelbourne Park
Orí pápáPlexicushion Prestige
Men's draw128S / 128Q / 64D
Women's draw128S / 96Q / 64D
Ẹ̀bùn owóA$23,140,000 (2009)[1]
Grand Slam
Close
Thumb
Rod Laver Arena je ikan ninu awon papa ibi ti Open Australia ti unwaye.

Itan

Open Australia koko bere bi Idije-eye Australasia (Australasian Championships) ko to wa di Idije-eye Australia (Australian Championships), ni 1927 to si di Open Australia (Australian Open) ni 1969.[3]. Open Australia di sisi sile, eyun open, fun awon osise agba tenis ni odun 1969, odun kan leyin ti awon idije Grand Slam meta yioku ti di open fun awon osise agba tenis.[4]



Itokasi

Wikiwand in your browser!

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.

Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.