From Wikipedia, the free encyclopedia
Austrálíà (o-STRAYL-yə,[4] or /ɔːˈstreɪliə/ aw-STRAY-lee-ə), fun ibise bi Orílẹ̀-èdè Àjọni ilẹ̀ Austrálíà, je orile-ede ni Southern Hemisphere to ni gbogbo ile orile Ostralia (to kere julo laye),[5][6] erekusu Tasmania, ati opolopo awon erekusu kekeke ni inu okun India ati Pasifiki.N4 Awon orile-ede to ni bode pelu ni Indonesia, East Timor, ati Papua New Guinea ni ariwa, Solomon Islands, Vanuatu, ati New Caledonia ni ariwa-ilaorun, ati New Zealand ni guusuilaorun.
Orílẹ̀-èdè Àjọni ilẹ̀ Austrálíà Commonwealth of Australia | |
---|---|
Olùìlú | Canberra |
Ìlú tótóbijùlọ | Sydney |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | None Note2 |
National language | English (de facto)Note2 |
Orúkọ aráàlú | Australian, Aussie[1][2] (colloquial) |
Ìjọba | Parliamentary democracy and constitutional monarchy, see Government of Australia |
• Monarch | King Charles III |
• Governor-General | Sam Mostyn |
• Prime Minister | Anthony Albanese |
Independence from the United Kingdom | |
• Constitution | 1 January 1901 |
• Statute of Westminster | 11 December 1931 |
• Statute of Westminster Adoption Act | 9 October 1942 (with effect from 3 September 1939) |
• Australia Act | 3 March 1986 |
Ìtóbi | |
• Total | 7,741,220 km2 (2,988,900 sq mi) (6th) |
• Omi (%) | 1 |
Alábùgbé | |
• 2008 estimate | 21,370,000[3] (53rd) |
• 2021 census | 25,890,773 |
• Ìdìmọ́ra | 3.4/km2 (8.8/sq mi) (192th) |
GDP (PPP) | 2007 estimate |
• Total | US$718.4 billion (IMF) (17th) |
• Per capita | US$34,359 (IMF) (14th) |
GDP (nominal) | 2008 estimate |
• Total | US$1046.8 billion (13th) |
• Per capita | US$49,271 (DFAT) (16th) |
HDI (2007) | 0.962 Error: Invalid HDI value · 3rd |
Owóníná | Australian dollar (AUD) |
Ibi àkókò | UTC+8 to +10.5 (variousNote3) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+9 to +11.5 (variousNote3) |
Àmì tẹlifóònù | 61 |
ISO 3166 code | AU |
Internet TLD | .au |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.