From Wikipedia, the free encyclopedia
Fránsì (pípè /ˈfræns/ ( listen) franss tabi /ˈfrɑːns/ frahns; French pronunciation (ìrànwọ́·ìkéde): [fʁɑ̃s]), fun ibise gege bi Ile Faranse Olominira (Faransé: République française, pípè [ʁepyblik fʁɑ̃sɛz]), je orile-ede ni apa iwoorun Europe, to ni opolopo agbegbe ati erekusu ni oke okun ti won wa ni awon orile miran.[10] Fransi je orile-ede onisokan olominira ti aare die ti bi o se n sise wa ninu Ipolongo awon eto Eniyan ati ti Arailu.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
French Republic République française Ilẹ̀ Faransé Olómìnira | |
---|---|
Motto: Liberté, Égalité, Fraternité "Òmìnira, Àparò-kan-ò-ga-jùkan-lọ, Ẹgbẹ́" | |
Orin ìyìn: "La Marseillaise" | |
Ibùdó ilẹ̀ Metropolitan France (orange) – on the European continent (camel & white) | |
Territory of the French Republic in the world | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Paris |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Faranse |
Orúkọ aráàlú | French |
Ìjọba | Unitary semi-presidential republic |
• Ààrẹ | Emmanuel Macron |
• Alákóso Àgbà | Michel Barnier |
Formation | |
• French State | 843 (Treaty of Verdun) |
• Current constitution | 1958 (5th Republic) |
Ìtóbi | |
• Total[1] | 674,843 km2 (260,558 sq mi) (40th) |
• Metropolitan France | |
551,695 km2 (213,011 sq mi) (47th) | |
543,965 km2 (210,026 sq mi) (47th) | |
Alábùgbé | |
(January 1, 2008 estimate) | |
• Total[1] | 64,473,140[4] (20th) |
• Metropolitan France | 61,875,822[5] (20th) |
• Ìdìmọ́ra[6] | 114/km2 (295.3/sq mi) (89th) |
GDP (PPP) | 2006 estimate |
• Total | US1.871 trillion (7th) |
• Per capita | US $30,100 (20th) |
GDP (nominal) | 2006 estimate |
• Total | US $2.232 trillion (6th) |
• Per capita | US $35,404 (18th) |
Gini (2002) | 26.7 low |
HDI (2005) | ▲ 0.952 Error: Invalid HDI value · 10th |
Owóníná | Euro,[7] CFP Franc[8] (EUR, XPF) |
Ibi àkókò | UTC+1 (CET[6]) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+2 (CEST[6]) |
Àmì tẹlifóònù | 33 |
Internet TLD | .fr[9] |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.