Wu Den-yih
From Wikipedia, the free encyclopedia
Wu Den-yih jẹ́ olóṣèlú ará Ṣáínà àti alákóso àgbà ní orílè-èdè Olóminira ilè Sáínà (Taiwan) láti ọjọ́ kẹwá oṣù kẹsán ọdún 2009..[1][2][3][4]. Ojo ibi re ogbon jo osu kinni, 1948. iyawo re ni Tsai ling-yi. o lo unifasiti gbogbo gbooo ti Saina.
Quick Facts Alakoso Agba Ile Olominira Ṣaina, Ààrẹ ...
Wu Den-yih 吳敦義 | |
---|---|
Alakoso Agba Ile Olominira Ṣaina | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 10 September 2009 | |
Ààrẹ | Ma Ying-jeou |
Deputy | Eric Liluan Chu |
Asíwájú | Liu Chao-shiuan |
Mayor of Kaohsiung | |
In office 15 June 1990 – 20 December 1998 | |
Asíwájú | Su Nan-cheng |
Arọ́pò | Frank Hsieh |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 30 Oṣù Kínní 1948 (1948-01-30) (ọmọ ọdún 76) Caotun, Republic of China |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Kuomintang |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Tsai Ling-yi |
Alma mater | National Taiwan University |
Close