Ma Ying-jeou
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ma Ying-jeou (Àdàkọ:Zh; Ọjọ ibi, Oṣu Keje 13, Ọdun 1950) ni Aare ikejila lowolowo orile-ede Olominira ile Saina (ROC), to gbajumo bi Taiwan, o tun je Alaga egbe oloselu Kuomintang, ti a mo gge bi Egbe Oloselu Asorile-ede ti Saina. Teletele o je Alakoso Oro Idajo lati 1993 de 1996, Baale ilu Taipei lati 1998 de 2006, ati Alaga Kuomintang (KMT) lati 2005 de 2007. Ma je didiboyan gege bi Baale ilu Taipei ni 1998 ati leekansi ni 2002. O je didiboyan bi Alaga Kuomintang ni Oṣu Keje Ọjọ 16, Ọdun 2005. O kosesile ni Kínní 13, Ọdun 2007, leyin ti o je fifesunkan latowo Ibise Afesunkan Giga Taiwan pelu esun ikowoje nigba ijoba re gege bi baale ilu Taipei;[1] won mu esun yi kuro nigbeyin. Ma bori ninu idiboyan aare odun 2008. O gori aga gege bi Aare ni Oṣu Karun ọjọ 20, Ọdun 2008, ati gege bi Alaga Kuomintang ni Oṣu Kẹwa 17, ọdun 2009.[2]
Ma Ying-jeou 馬英九 | |
---|---|
12th-term President of the Republic of China | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga May 20, 2008 | |
Premier | Liu Chao-shiuan Wu Den-yih |
Vice President | Vincent Siew |
Asíwájú | Chen Shui-bian |
6th Chairman of the Kuomintang | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga October 17, 2009 | |
Asíwájú | Wu Po-hsiung |
4th Chairman of the Kuomintang | |
In office July 27, 2005 – February 13, 2007 | |
Asíwájú | Lien Chan |
Arọ́pò | Wu Po-hsiung |
Mayor of Taipei | |
In office December 25, 1998 – December 25, 2006 | |
Asíwájú | Chen Shui-bian |
Arọ́pò | Hau Lung-pin |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 13 Oṣù Keje 1950 (1950-07-13) (ọmọ ọdún 73) Yau Ma Tei, Kowloon, Hong Kong |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Republic of China |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Kuomintang |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Christine Chow Ma |
Alma mater | National Taiwan University New York University Harvard University |
Website | www.president.gov.tw |