Surulere jẹ́ ibùgbé àti ibi iṣòwò agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ tó wà ní òke-odò ní Ìlú Èkó ní ìpínlẹ̀ Èkó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, agbègbè yíi tó ìwọn 23 km². ìkànìyàn tí wọ́n ṣe ní ọdún 2006 fihàn wípé ó kéré jù ènìyàn 503,975 ń gbé agbègbè yìi pẹ̀lú ìṣúpọ̀ olùgbé bíi 21,864 fún ìdá kan km².

Quick Facts Orílẹ̀ èdè, Ìpínlẹ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ...
Surulere
Thumb
Ibi t́ ó wà ní Ìlú Èkó
Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Ìpínlẹ̀ ní orílẹ̀ èdè NàìjíríàÌpínlẹ̀ Èkó
Area
  Total23 km2 (9 sq mi)
Population
  Total503,975
  Density22,000/km2 (57,000/sq mi)
Time zoneUTC+1 (CET)
Close

Àkópọ̀

Ibẹ̀ ni pápá ìdárayá ti orílë-èdè (ó gba èèyan 60,000) tí wọ́n kọ́ sí Ìlú Èkó ní ọdún 1972 fún eré ìdárayá gbogbo ilẹ̀ Áfíríkà wà. Pápá ìdárayá yìi ti ń di àkọ̀tí lati ọdún 2002.[1] Síbẹ̀síbẹ̀, fún ìgbaradì fún ìdíje Under 17 FIFA World Cup tó wáyé ní ọdún 2009, ohun èlò pápá ìdárayá yìi rí àmójútó díẹ̀, ìdíje yií bẹ̀rẹ̀ láìsí ìdíwọ́ ní Oṣù kéwa ọdún 2009.[2][3]

Àwọn ìtọ́kasí

Ìjápọ Ìtà

Wikiwand in your browser!

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.

Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.