Serena Williams
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America / From Wikipedia, the free encyclopedia
Serena Jameka Williams (ojoibi September 26, 1981) je agba boolu Tenis omo orile-ede Amerika lowolowo to wa Eniipo kinni lagbaye ninu idije enikan ati Eniipo keji ninu idije enimeji pelu egbon re Venus Williams(12/8/10). Ijose Tenis awon Obinrin (WTA) ti fisipo kini lagbaye ni igba otooto marun. O tun ipo kinni gba fun igba karun ni ojo 2 Osu Kokanla 2009. O koko bo si ipo kinni lagbaye ni ojo 8 Osu Kejo 2002. Ni ojo 3 Osu Keje 2010, o di eni kefa lori akojo awon oludijeakoko olokikijulo gbogbo igba lailai.[5]
Ni 2014 | |
Orílẹ̀-èdè | United States |
---|---|
Ibùgbé | Palm Beach Gardens, Florida, United States[1] |
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kẹ̀sán 1981 (1981-09-26) (ọmọ ọdún 42) Saginaw, Michigan, United States |
Ìga | 5 ft 9 in (1.75 m)[1] |
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | September 24, 1995 |
Ọwọ́ ìgbáyò | Owo-otun (igbaeyin olowo-meji) |
Ẹ̀bùn owó | US$ 73,293,424[2] (1st all-time among women athletes and 4th all-time among tennis athletes)[3] |
Ojúewé Íntánẹ́ẹ̀tì | serenawilliams.com |
Iye ìdíje | 783–130 (85.76%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 73 WTA[1] (4th in overall rankings) |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 1 (July 8, 2002) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 1 (June 6, 2016)[4] |
Open Austrálíà | Ay (2003, 2005, 2007, 2009, 2010, 2015, 2017) |
Open Fránsì | Ay (2002, 2013, 2015) |
Wimbledon | Ay (2002, 2003, 2009, 2010, 2012, 2015, 2016) |
Open Amẹ́ríkà | Ay (1999, 2002, 2008, 2012, 2013, 2014) |
Ìdíje WTA | Ay (2001, 2009, 2012, 2013, 2014) |
Ìdíje Òlímpíkì | Ẹ̀ṣọ́ wúrà (2012) |
Iye ìdíje | 169-22 (89.1%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 22 |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 1 (June 7, 2010) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 64 (September 23, 2013) |
Open Austrálíà | Ay (2001, 2003, 2009, 2010) |
Open Fránsì | Ay (1999, 2010) |
Wimbledon | Ay (2000, 2002, 2008, 2009, 2012, 2016) |
Open Amẹ́ríkà | Ay (1999, 2009) |
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn | |
Ìdíje WTA | SF (2009) |
Ìdíje Òlímpíkì | Ẹ̀ṣọ́ wúrà (2000, 2008, 2012) |
Iye ìdíje | 27–3 (90%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 2 |
Open Austrálíà | F (1999) |
Open Fránsì | F (1998) |
Wimbledon | Ay (1998) |
Open Amẹ́ríkà | Ay (1998) |
Fed Cup | Ay (1999) |
Hopman Cup | Ay (2003, 2008) |
Last updated on: August 31, 2015. |
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki | |||
Tẹ́nìs àwọn obìnrin | |||
---|---|---|---|
Adíje fún USA | |||
Wúrà | 2000 Sydney | Ẹniméjì | |
Wúrà | 2008 Beijing | Ẹniméjì | |
Wúrà | 2012 London | Ẹnìkan | |
Wúrà | 2012 London | Ẹniméjì |
Williams ni oludijeakoko lowolowo ni idije enikan ati enimeji awon obinrin ni Open Australia, oludijeakoko lowolowo idije enikan ni Wimbledon, ati ni idije enimeji awon obinrin ni Open Faranse ati ni Open Amerika. Awon ife-eye Grand Slam mejilelogbon to gba fun ni ipo kefa lori akojo gbogbo igba lailai: 17 ni idije awon obinrin enikan, 13 ni idije awon obinrin enimeji, ati 2 ni idije adapo enimeji. Ohun ni agbayo laipe yi, obinrin abi okunrin, to gba gbogbo awon ife-eye Grand Slam mereerin leekanna, ati obinrin ikarun lailai to se be. Awon ife-eye Grand Slam 17 re ni ikefa lori akojo gbogbo igba lailai.[6] Williams je ikerin bii awon ife-eye Grand Slam awon obinrin to gba n'Igba Open, leyin Steffi Graf (ife-eye 22) ati Chris Evert ati Martina Navratilova (ife-eye 18).[6] O ti gba awon ife-eye Grand Slam ni idije enikan, awon obinrin enimeji ati adapo enimeji ju obinrin agbayo miran lo lowolowo.
Williams ti gba eso wura Olimpiki ikan ninu idije awon obinrn enikan ati meta ninu idije awon obinrin enimeji pelu egbon re Venus Williams.[7] Williams ti gba ebun owo fun ise ju obinrin elere-idaraya miran lo lailai.[8] Williams ni aburo Venus Williams to ti wa ni ipo kinni lagbaye tele. Won ti ba ara won gbayo nigba 23 idije alagbase lati 1998, Serena bori ni 17 awon idije wonyi titi di Osu Kewa 2013. Titi di Osu Keje 2009, won ti pade ni opin idije Grand Slam mejo, Serena bori ni emefa. Larin Open Faranse 2002 ati Open Australia 2003, won pade ni opin awon idije enikan gbogbo Grand Slam mererin, igba akoko ni igba open ti awon oludije meji kanna dije fun opin Grand Slam ni titelentele. Awon mejeji ti gba ife-eye Grand Slam 12 idije enimeji bi ikanna.