Samuel Ortom
Olóṣèlú / From Wikipedia, the free encyclopedia
Samuel Ioraer Ortom tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹrin ọdún 1961 (23rd April 1961) jẹ́ òṣèlú, oníṣòwò àti aláàánú ọlọ́rẹ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Benue lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni Gómìnà Ìpínlẹ̀ Benue kí ó tó di ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ́n oṣù karùn-ún ọdún 2023, tí àlùfáà ìjọ Kátólíìkì Hyacinth Iormem Alia dípò rẹ̀ lẹ́yìn ìdìbò gbogboògbò ọdún 2023. Lọ́dún 2015 ló wọlé gẹ́gẹ́ bí gómìnà lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́ òṣèlú APC, nígbà tó di ọdún 2019, ó tún wọlé gẹ́gẹ́ bí gómìnà ìpínlẹ̀ Benue fún sáà kejì ṣùgbọ́n lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP. Nígbà ìṣèjọba Ààrẹ ana, Goodluck Jonathan, Samuel Ortom ni Mínísítà abẹ́lé fún karai àti dídá Okowò sílẹ̀.
Quick Facts 18th Governor of Benue State, Asíwájú ...
Samuel Ioraer Ortom | |
---|---|
18th Governor of Benue State | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga May 2015 | |
Asíwájú | Gabriel Suswam |
Federal Minister of Industry, Trade and Investment Nigeria | |
In office 11 July 2011 – 25 October 2015 | |
Supervising Minister, Nigerian Federal Ministry of Aviation Nigeria | |
In office 14 February 2014 – 15 August 2014 | |
Asíwájú | Princess Stella Oduah-Ogiemwonyi |
Arọ́pò | Osita Chidoka |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 23 April 1961 Guma LGA, Benue State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | PDP |
Close