Hyacinth Alia
From Wikipedia, the free encyclopedia
Hyacinth Iormem Alia (wọ́n bí lọ́jọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún, oṣù karùn-ún ọdún, 1966) jẹ́ òṣèlú ọmọ Nigeria àti àlùfáà ìjọ Kátólíìkì tí ó di gómìnà Ìpínlẹ̀ Benue láti ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ́n oṣù karùn-ún ọdún 2023.[1][2][3]
Quick Facts 19th Governor of Benue State, Deputy ...
Hyacinth Iormem Alia | |
---|---|
19th Governor of Benue State | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ́n oṣù karùn-ún ọdún (29/5) 2023 | |
Deputy | Samuel Ode |
Asíwájú | Samuel Ortom |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 15 Oṣù Kàrún 1966 (1966-05-15) (ọmọ ọdún 57) Mbangur, Mbadede, Vandeikya, Ìpínlẹ̀ Benue, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress |
Occupation | Politician, Catholic priest |
Close