From Wikipedia, the free encyclopedia
Àdàkọ:Infobox order
Nàìjíríà gba olómìnira ní ayájọ́ ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá 1960, ó sì di orílẹ̀-èdè olómìnira ní ọdún 1963. Orílẹ̀-èdè yí ṣe agbékalẹ̀ amì-ẹ̀yẹ ìdánilọ́lá méjì kan kalẹ̀ láti ma fi bu ọlá fún àwọn lààmì-laaka ènìyàn láwùjọ. Àwọn àmì-ẹ̀yẹ náà ni: Order of the Niger àti Order of the Federal Republic.[1]
Àwọn amì-ẹ̀yẹ méjì tí wọ́n lákaakì jùlọ nínú àwọn amì-ẹ̀yẹ náà ni: Grand Commander in the Order of the Federal Republic . Ìsọ̀rí àkọ́kọ́ yí jẹ́ amì-ẹ̀yẹ tí ó tọ́ sí ẹnikẹ́ni tí ó bá ti jẹ Ààrẹ àti igbákejì Ààrẹ, Olórí ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin, Adájọ́ Àgbà fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kọ́ṣe ìjọba ìjọba àmúnisìn ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì nípa fífi amì-ẹ̀yẹ da àwọn lààmì-laaka àti ọ̀tọ̀kùlú ìlú lọ́lá. Amì-ẹ̀yẹ yí ni ó wà fún àwọn ológun àti àwọn tí kìí ṣe ológun. Wọ́n sì ma ń kọ̀wé ránṣẹ́ sí àwọn tí wọ́n bá yàn láti fi amì-ẹ̀yẹ náà dá lọ́lá.
S/NO | Orúkọ | Ipò | Sector | Irúfẹ́ amì-ẹ̀yẹ |
---|---|---|---|---|
1 | Joseph Wayas | Former Senate President | Public | GCON |
2 | Aliko Dangote | Chairman of Dangote Group | Private | GCON |
3 | Bello Maitama Yusuf | Former Internal Affairs Minister | Public | GCON |
4 | Aminu Tambuwal | Speaker House of Representatives, Governor of Sokoto State | Public | CFR |
5 | Mohammed Bello Adoke, SAN | Attorney General of the Federation | Public | CFR |
6 | Oluseyi Petinrin | Chief of Defence Staff | Public | CFR |
7 | Muhammadu Dikko | Chief of Air Staff (CAS) | Public | CFR |
8 | Azubuike Ihejirika | Chief of Army Staff | Public | CFR |
9 | Hafiz Ringim | Former Inspector General of Police | Public | CFR |
10 | Abdullahi Dikko | Former Comptroller General of Police | Public | CFR |
11 | Aloma Mariam Mukhtar | Former Justice of the Supreme Court | Public | |
12 | Victoria Gowon | Former First Lady of Nigeria | Public | CFR |
13 | Bolaji Akinyemi | Scholar, diplomat, former minister | Public | CFR |
14 | Chinua Achebe | Scholar, eminent writer | Private | CFR |
15 | Folagbade Olateru Olagbegi III | The Olowo of Owo | Private | CFR |
16 | Tony Elumelu | Philanthropist | Private | CON |
17 | Ahmed Idris Wase | Deputy Speaker House of Representatives | Public | CON |
18 | Oba Otudeko | Business | Private | CON |
19 | Akin Mabogunje | Consultant, business | Private | CON |
20 | Peter Obi | Former Governor of Anambra State | Public | CON |
21 | Liyel Imoke | Former Governor of Cross River State | Public | CON |
22 | Adams Oshiomhole | Former Governor of Edo State | Public | CON |
23 | Patrick Ibrahim Yakowa | Former Governor of Kaduna State | Public | CON |
24 | Ibrahim Shehu Shema | Former Governor of Katsina Staff | Public | CON |
25 | Mu'azu Babangida Aliyu | Former Governor of Niger State | Public | CON |
26 | Rotimi Amaechi | Former Governor of Rivers State | Public | CON |
27 | Godswill Akpabio | Former Governor of Akwa Ibom State | Public | CON |
28 | Sule Lamido | Former Governor, Jigawa State | Public | CON |
29 | Abba Kyari | Former Governor North Central State | Public | CON |
30 | Chukwuemeka Ezeife | Former Governor Anambra Staff | Public | CON |
31 | Olusegun Agagu | Former Governor of Ondo State, geologist | Public | CON |
32 | Isiaka Adeleke | Former Governor of Osun State, Senator | Public | CON |
33 | Lam Adesina | Former Governor of Oyo State | Public | CON |
34 | Bukar Abba Ibrahim | Former Governor of Yobe State, Senator | Public | CON |
35 | Rufus Ada George | Former Governor of Rivers State | Public | CON |
36 | Atedo Peterside | Banker | Private | CON |
37 | Sam Ohuabunwa | Pharmacist, industrialist, administrator | Private | OFR |
38 | Tony Ezenna | Business, industrialist | Private | OFR |
39 | Iyorwuese Hagher | Former Minister of State for Health/Power and Steel and Ambassador to Mexico and High Commissioner to Canada[3] | Public | OON |
40 | Victor Olaiya | Musician | Private[4][5] | OON |
41 | Francesca Yetunde Emanuel | Former permanent secretary | Public | CON |
42 | Stella Oduah | Former Minister of Aviation | Public | OON |
43 | Tobi Amusan | Athlete | Sport | OON |
44 | Iyin Aboyeji | Former CEO, Flutterwave & Co-founder, Andela | Private | OON |
45 | Teni | Teni | Private | MON |
46 | Emeka Okwuosa | Chairman/GCEO, OilServ Limited | Private | CON |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.