Open Fránsì 2002 − Àwọn Obìnrin Ẹnìkan
From Wikipedia, the free encyclopedia
Jennifer Capriati lo je ayori lodun to lo, sugbon o pofo lowo Serena Williams ni idaji-ipari, ni eyi to je atun ayo gba ayo ti won bara won gba ni Open Fransi odun to lo.
More information Àwọn ìdíje, Other events ...
Open Fránsì 2002 | ||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Ayọrí | ![]() | |||||||||||
Onípò kejì | ![]() | |||||||||||
Èsì | 7–5, 6–3 | |||||||||||
Àwọn ìdíje | ||||||||||||
Ẹnìkan | ọkùnrin | obìnrin | boys | girls | ||||||||
Ẹniméjì | men | women | mixed | boys | girls | |||||||
Other events | ||||||||||||
Legends | 45+ | |||||||||||
WC Singles | ||||||||||||
WC Doubles | ||||||||||||
Open Fránsì
| ||||||||||||
Close
Williams bori egbon re, Venus ni ipari, lati gba ife-eye Open Fransi re akoko. Eyi na tun ni igbese re akoko lati se "The Serena Slam".