![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/yo/thumb/e/ef/Kanu.jpg/640px-Kanu.jpg&w=640&q=50)
Nwankwo Kanu
Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà / From Wikipedia, the free encyclopedia
Nwankwo Christian Nwosu Kanu, OON (ojoibi 1 August 1976 in Owerri, Nigeria), tabi Kanu lasan, je alagbata agbaboolu-elese omo ile Naijiria to un gba iwaju fun egbe alagbata ni Football League Championship, Portsmouth. O tun pile ti je omo egbe agbaboolu omoorile-ede Naijiria fun odun 16 lati 1994 titi di 2010. Kanu wa lati egbe eya eniyan Igbo;[1] oruko re, Nwankwo, tumosi Odo mokunrin ti abi ni ojo oja Nkwo ni ede Igbo.[2].
Àyọkà yìí únfẹ́ ìyílédèdà sí Yorùbá. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ ṣàtúnṣe sí ìyílédèdà |
![]() | |||||||||||||
Nípa rẹ̀ | |||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Orúkọ | Nwankwo Nwosu Kanu | ||||||||||||
Ọjọ́ ìbí | 1 Oṣù Kẹjọ 1976 (1976-08-01) (ọmọ ọdún 47) | ||||||||||||
Ibùdó ìbí | Owerri, Nigeria | ||||||||||||
Ìga | 1.97 m (6 ft 5 | ||||||||||||
Ipò | Second striker | ||||||||||||
Nípa ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lùtà | |||||||||||||
Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lùtà lọ́wọ́ | Portsmouth | ||||||||||||
Nọ́mbà | 27 | ||||||||||||
Alágbàtà* | |||||||||||||
Odún | Ẹgbẹ́ | Ìkópa† | (Gol)† | ||||||||||
1991–1992 | Fed Works | 35 | (20) | ||||||||||
1992–1993 | Iwuanyanwu Nationale | 25 | (15) | ||||||||||
1993–1996 | Ajax | 54 | (25) | ||||||||||
1996–1999 | Internazionale | 12 | (1) | ||||||||||
1999–2004 | Arsenal | 119 | (30) | ||||||||||
2004–2006 | West Bromwich Albion | 53 | (7) | ||||||||||
2006– | Portsmouth | 115 | (17) | ||||||||||
Agbábọ́ọ̀lù ọmọorílẹ̀-èdè‡ | |||||||||||||
1993 | Nigeria U17 | 6 | (5) | ||||||||||
1996 | Nigeria U23 | 6 | (3) | ||||||||||
1994–2010 | Nigeria | 84 | (13) | ||||||||||
Àwọn àyẹ̀lé
| |||||||||||||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 17:45, 26 December 2010 (UTC). † Appearances (Goals). |
Kanu gba eso UEFA Champions League kan, eso Ife-eye UEFA kan, Eso Abori Ife-eye FA meta ati ebun Ara Afrika Agbaboolu-Elese Ododun meji. O tun je ikan ninu awon agbaboolu ti won ti gba Premier League, Ife-eye FA, Champions League, Ife-eye UEFA ati Eso Wura Olympiki.[3] Bakanna o tun je alabasoju UNICEF.[4].