Nnamdi Azikiwe
Olóṣèlú / From Wikipedia, the free encyclopedia
Àdàkọ:Infobox Aarẹ
![Thumb image](http://upload.wikimedia.org/wikipedia/yo/e/e5/Zik.jpg)
Benjamin Nnamdi Azikiwe (November 16, 1904 – May 11, 1996) tabi Zik jẹ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, láti ẹ̀yà Igbo. Ọkan ninu awon ólósèlú pàtàkì ni Azikiwe jẹ ni Nàìjíríà, o si jẹ asíwájú fun Ifegbega orile-ede ara ẹni ni Nàìjíríà lodeoni, bẹ sini o tun jẹ Aare ile Naijiria akọkọ ni Ìgbà Òṣèlú Àkọ́kọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà leyin igbati Nàìjíríà gba ominira ni odun 1960.[1][2]