Mark ZuckerbergFrom Wikipedia, the free encyclopedia Mark Elliot Zuckerberg tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlá oṣù karùn-ún ọdún 1984 (14 May 1984) jẹ́ oníṣòwò ayélujára, afọwọ́ṣàánú àti ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ àti Aláṣẹ yánányán ìkànnì abánidọ́rẹ̀ẹ́, Facebook ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. [1] [2] [3] [4] -Mark Zuckerberg (2014)
Mark Elliot Zuckerberg tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlá oṣù karùn-ún ọdún 1984 (14 May 1984) jẹ́ oníṣòwò ayélujára, afọwọ́ṣàánú àti ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ àti Aláṣẹ yánányán ìkànnì abánidọ́rẹ̀ẹ́, Facebook ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. [1] [2] [3] [4] -Mark Zuckerberg (2014)