From Wikipedia, the free encyclopedia
Lucy Allais jẹ onímọ̀ nínú ẹ̀kọ́ ìmòye, tó jẹ́ olùkọ́ ní University of Witwatersrand àti Johns Hopkins University.[1] Àwọn iṣẹ́-ìwádìí rẹ̀ dá lórí ìwòye Immanuel Kant lórí ìdáríjì, ìjìyà àti ìmọ̀-ìjìnlẹ̀. [2]
Allais gba oyè ẹ̀kọ́ nínú ẹ̀kọ́ ìmòyè ní University of Witwatersrand (Wits), ní Johannesburg, lẹ́yìn náà ló gba oyè ẹ̀kọ́ (B.Phil.) àti D.Phil. ní University of Oxford. Ó sì tẹ̀síwájú láti lọ máa ṣiṣẹ́ olùkọ́ni ní Oxfors fún ọdún mẹ́ta léyìn tó gba oyè D.Phil., kí ó ṣẹ̀ tó wá lọ sí University of Sussex ní ọdún 2004. Láàárín ọdún 2006 àti 2008 Dr. Allais ṣiṣẹ́ olùkọ́ni ní University of Witwatersrand. Ní ọdún 2008, Allais bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ọ̀na méjì ní University of the Witwatersrand, níbi tí ó ti jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n, àti University of Sussex.[3] Ní ọdún 2014 ó kúrò ní Sussex lọ sí University of California, San Diego, gẹ́gẹ́ bí i Henry E. Allison, tó sì jẹ́ alága History of Philosophy, tí ó sì ń ṣiṣẹ́ náà pọ̀ mọ́ Witwatersrand.[4] [5] Ó fi UCSD sílẹ̀ láti lọ sí Johns Hopkins ń ọdún 2021.[6]
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.