Kòlómbìà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Kòlómbìà (pípè /kəˈlʌmbiə/), fun onibis bi Orile-ede Olominira ile Kolombia (Spánì: [República de Colombia] error: {{lang}}: text has italic markup (help), pronounced [reˈpuβlika ðe koˈlombja] ( listen)), je orile-ede olominira onilana-ibagbepo ni ariwaapaiwoorun Guusu Amerika. Kolombia ni bode ni ilaorun pelu Venezuela[6] ati Brazil;[7] ni guusu pelu Ecuador ati Peru;[8] ni ariwa pelu Okun Karibeani; ni ariwailaorun pelu Panama; ati ni iwoorun pelu Okun Pasifiki. Bakanna Kolombia tun pin bode odo pelu Venezuela, Jamaica, Haiti, Dominiki Olominira, Honduras, Nicaragua ati Costa Rica.[9][10] Pelu iye awon eniyan to to egbegberun 45, Kolombia ni iye eniyan 29th titobijulo lagbaye ati ikeji titobijulo ni Guusu Amerika, leyin Brazil.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kòlómbìà Republic of Colombia República de Colombia (Híspánì)
| |
---|---|
Motto: "Libertad y Orden" (Híspánì) "Liberty and Order" | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Bogotá |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Spanish1 |
Lílò regional languages | The languages and dialects of ethnic groups are also official in their territories.[1] |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | 58% Mestizo 21% Afro Colombian 20% White 1% Amerindian[2] |
Orúkọ aráàlú | Colombian |
Ìjọba | Unitary presidential republic |
• President | Gustavo Petro |
• Vice President | Francia Márquez |
Independence From Spain | |
• Declared | July 20, 1810 |
• Recognized | August 7, 1819 |
• Current constitution | 1991 |
Ìtóbi | |
• Total | 1,138,910 km2 (439,740 sq mi) (26th) |
• Omi (%) | 8.8 |
Alábùgbé | |
• March 2010 estimate | 45,393,050[3] (29th) |
• 2005 census | 42,888,592[3] |
• Ìdìmọ́ra | 40/km2 (103.6/sq mi) (168th) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $401.966 billion[4] |
• Per capita | $9,200[4] |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $228.836 billion[4] |
• Per capita | $5,087[4] |
Gini (2006) | 52 high |
HDI (2007) | ▲ 0.807 Error: Invalid HDI value · 77th |
Owóníná | Peso (COP) |
Ibi àkókò | UTC-52 |
Irú ọjọ́ọdún | dd-mm-yyyy (CE) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | otun |
Àmì tẹlifóònù | +57 |
Internet TLD | .co |
|
Agbegbe ti a n pe ni Kolombia loni koko je ibugbe awon ara abibibi bi Muisca, Quimbaya, ati Tairona. Awon ara Spein debe ni 1499 won si bere isegun ati iseamusinibe, won fikupa tabi se ikoleru bi 90% awon eniyan ibe, nigbana ni won sedasile Ibasorun ile Grenada Tuntun (to ni ile odeoni Colombia, Venezuela, Ecuador, ariwaiwoorun agbegbe ile Brazil ati Panama) pelu oluilu re ni Bogotá.[11] Ilominira latowo Spain waye ni 1819, sugbon ni 1830 "Gran Colombia" daru eyi fa ki Venezuela ati Ecuador o pinya soto. Awon ti a mo loni bi Kolombia ati Panama di Orile-ede Olominira ile Grenada Tuntun. Orile-ede tuntun yi sedanwo ijoba isealapapo gege bi Ijosepapo Grenada (1858), ati leyin re bi Iparapo awon Ipinle Kolombia (1863), ki o to dipe won kede Orile-ede Olominira ile Kolombia nigbeyin ni 1886.[2] Panama pinya ni 1903 labe ifitipatipa sanwo fun ijoba orile-ede Amerika lati ko Ìladò Panamá.