J. E. A. Wey
Olóṣèlú / From Wikipedia, the free encyclopedia
Joseph Edet Akinwale Wey (ojoalaisi 12 December 1990) [1] je omose ologun ojuomi orile-ede Naijiria to figba kan je, bi olori Ile-ise Ologun Ojuomi Naijiria,[2] adipo Alakoso Oro Okere,[3] ati Oga Gbogbo Omose Ologun ni Ibujoko Togajulo,[4] eyi to so di de facto Igbakeji Aare ile Naijiria nigba ijoba Yakubu Gowon. O fi tipatipa feyinti nigba ti Murtala Mohammed fitipagbajoba lowo Gowon.[4]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Quick Facts Vice Admiral/Igbakeji Adarioko-ogunojuomi Joseph Edet Akinwale Wey, 2nd Vice President of Nigeria ...
Vice Admiral/Igbakeji Adarioko-ogunojuomi Joseph Edet Akinwale Wey | |
---|---|
2nd Vice President of Nigeria | |
In office July 29, 1966 – July 29, 1975 | |
Ààrẹ | Yakubu Gowon |
Asíwájú | Babafemi Ogundipe |
Arọ́pò | Olusegun Obasanjo |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | None (military) |
Close