![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/0/09/Olusegun_Obasanjo_%2528Brasilia_6_September_2005%2529.jpg/640px-Olusegun_Obasanjo_%2528Brasilia_6_September_2005%2529.jpg&w=640&q=50)
Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́
Olóṣèlú / From Wikipedia, the free encyclopedia
Matthew Àrẹ̀mú Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ GCFR[1] (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ karùn-ún oṣù kẹta ọdún 1937) jẹ́ gbajúmọ̀ àgbà olóṣèlú, ajagun-fẹ̀yíntí àti Ààrẹ àná orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Orúkọ bàbá rẹ̀ ni Amos Àdìgún Ọbalúayésanjọ́ "Obasanjo" Bánkọ́lé, ìyá rẹ̀ sìn ń jẹ́ Àṣàbí.Ọbásanjọ́ jẹ́ ọmọ bíbí Òwu ní ìlú Abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ìyá rẹ̀ kú ní ọdún 1958, bàbá rẹ̀ sìn kú bákan náà ní ọdún 1959.
Quick Facts Olusegun Obasanjo, Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà 12k ...
Olusegun Obasanjo | |
---|---|
![]() | |
Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà 12k | |
In office 29 May, 1999 – 29 May, 2007 | |
Vice President | Atiku Abubakar |
Asíwájú | Abdulsalami Abubakar |
Arọ́pò | Umaru Yar'Adua |
5th Olori Orile-ede Naijiria | |
In office February 13, 1976 – October 1, 1979 | |
Vice President | Shehu Musa Yar'Adua |
Asíwájú | Murtala Mohammed |
Arọ́pò | Shehu Shagari |
3rd Vice President of Nigeria | |
In office July 29, 1975 – February 13, 1976 | |
Ààrẹ | Murtala Mohammed |
Asíwájú | J.E.A. Wey |
Arọ́pò | Shehu Musa Yar'Adua |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Kẹta 1937 (1937-03-05) (ọmọ ọdún 87) Abeokuta, Ipinle Ogun, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Lynda Obasanjo (ex-wife, aláìsí), Stella Obasanjo (aláìsí) |
Close